Uncategorized

All Videos : 11  Video Posted

BUHARI OSIBAJO @nigezietv BUHARI OSIBAJO @nigezietv Watch Video
Buhari So Wipe Oun Ko Pada Wa Lati Se Aare O, Ki Osibajo Go On Sohun

orisun

10/03/2017

377

Buhari oada de si Orile Ede Nigeria loni Ojo kewa osu keta odun 2017 so wipe oun gbe gbogbo agbara lati se ijoba fun igbakeji oun, Prof. Osibajo. Buhari pada si Nigeria loni leyin ojo mokandinlaadota ti o fi gba isinmi lo si Ilu London.

Watch Video
fASHOLA AMBODE @nigezietv fASHOLA AMBODE @nigezietv Watch Video
Fashola Ni Ko Je Ki A Tun Ilu Eko Se O – Ambode

orisun

10/03/2017

251

Gomina Ipinle Eko, Iyen Akinwunmi Ambode fi esun kan Babatunde Raji Fashola ti o je Minisita fun Ise ati gbigbe awon eniyan fun bi o ti moomo da ise oun ru; ati wipe, ko je ki akitiyan oun han fun itoju ati igbelaruge/Isodotun Ilu-Eko.

Watch Video
Dimitri Payet Dimitri Payet Watch Video
Dimitri Payet Joins Marseille From West Ham

orisun

30/01/2017

205

Olympique de Marseille have signed France forward Dimitri Payet on a 4-1/2 year contract from West Ham United after they agreed a transfer fee of 25 million pounds

Watch Video
DUFADA DUFADA Watch Video
Ah Iya Ma Je Mi Ooooo Dufada

orisun

25/01/2017

242

Ah Iya Ma Je Mi Ooooo Dufada. Oluranlowo igbakan ri fun Aare ano Ebele Goodluck Jonathan ti fi esun kan ajo EFCC pe won n lo awon iwe-eri ti kii se oto lati tembelu ohun.

Watch Video
Dayo Amusa Dayo Amusa Watch Video
IJOYA: DAYO AMUSA (@dayoamusa) – BLOW YOUR MIND

orisun

25/01/2017

839

Dayo Amusa the famous nollywood actress is back with another banging tune titled Blow your mind. The video was directed by HG2 Film, features Zeez with a steamy romance with the award-winning and internationally acclaimed Dayo Amusa.

Watch Video
MADUEKE MADUEKE Watch Video
Emi O ji Owo Nigeria O Alison Madueke

orisun

23/01/2017

238

Emi O ji Owo Nigeria O Alison Madueke ni o so eleyi. Asoju agbe eto epo-robi ti orile -ede Nigeria Arabinrin Alison Madueke ti doju ko ajo EFCC ti o si so wipe ohun ko ji owo Nigeria.

Watch Video
mmm mmm Watch Video
Won Ko Si AKaanti MMM Temi O, Omo Kogi Kan Ni O so Bee

orisun

14/01/2017

277

Awon Odo kan ni won da pati sile ni ilu Kogi loni lati fi se ajoyo ipadabo MMM. Akoroyin wa so wipe Nise ni awon odo ti o po wa ni ile-oti kaakakiri Ilu naa ninu ayo wipe MMM ti si pada.

Watch Video
V.I.O V.I.O Watch Video
Ajo V.I.O Se Ikilo Pataki Fun Awon Awako Ero

orisun

05/01/2017

181

Ajo V.I.O ti ilu eko ti se ikilo pataki fun awon awako ilu eko lati ri daju pe iwe oko won ati iwe ase iwako awako pe pere-pere ko to dipe ajo V.I.O yi o bere ise won ni perehu

Watch Video
Ooni Of Ife Ooni Of Ife Watch Video
You’re An Illiterate, Traditional Rulers At WAR Over Ooni Of Ife

orisun

28/12/2016

225

You’re An Illiterate, Traditional Rulers At WAR Over Ooni Of Ife The traditional ruler of Igbotako and Rebuja of Osooro kingdom, in Ondo state, Oba Gbadebo Bajowas, has slammed the Olugbo of Ugbo kingdom, Oba Fedrick Obateru Akinruntan for disrespecting Ooni

Watch Video
image Watch Video
Nje Iwe Eri (Certificate) Ile Wa Nigeria Se O Wulo

orisun

11/12/2016

171

Nje Iwe Eri (Certificate) Ile Wa Nigeria Se O Wulo Nje Iwe Eri (Certificate) Ile wa Nigeria Shi je atewo gba ni ilu okere. Atokun Babajide Morunfola lori eto Eji Owuro pelu akawe gboye Dr. Akeem      

Watch Video