OWAMBE

All Videos : 3  Video Posted

image Watch Video
1
Ayeye Oku Baba Eniola Badmus Ni Ilu Eko

orisun

25/08/2017

135

Osere ere agbelewo ti o kopa ninu ere "Jenifa", Eniola Badmus ti gbogbo ilu mo si Gbogbo bigz girl se eto isnku baba re lai pe yii.

Watch Video
alibaba alibaba Watch Video
2
Aderinposonu Alibaba Tun gbe Eto Odoodun Ti January Kale

orisun

15/01/2017

122

Gege bi Alibaba ti maa n se lodoodun, Alibaba January 1st. Lati gbe awon aderinposonu bii tie lati mu ori ya ati pa awon eniyan lerin. Opolopo Olorin ni o wa nibe bii, olamide. Tiwa Savage, Niyola ati beebee lo. E wo fidio yii ki e gbo nnkan ti awon eniyan so

Watch Video
igbeyawo igbeyawo Watch Video
1
ETO IGBEYAWO LAARIN SIDIKAT ATI IBRAHIM

orisun

03/01/2017

157

Eto igbeyawo laye, Oba oluwa lo fi lele pelu ase. Opolopo elere ati gbajumo ni o wa fun ayeye igbayawo naa. Alhaji Ayinde Wasiu ni o Korin nibe Orin ti o ko, e o tii gbo ri.

Watch Video