OJURI

All Videos : 10  Video Posted

image Watch Video
3
#OJURI: Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

orisun

12/12/2017

206

Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju? Lori Eto Ojuri loni, Aralomo presenter bere lowo alejo re nipa awon nnkan ti awon omo le se lati fi ja fun eto won lati owo obi won. Bi awon omode se ni eto lati gba itoju gidi, aralomo bere nipa<

Watch Video
image Watch Video
3
Olopa O Leto Lati Gba Owo Ki Won To Fi Eyan Sile

orisun

22/08/2017

190

Police (Olopa) je ajo ti on gbe ofin ro ni ilu nigeria ti o sumo awon ara ilu. Opo igba si ni awon Olopa (police) ti ma n se bo se wu won. Awon ara ilu si ti pariwo si ijoba leti lori orisirisi asemase ti awon Olopa (police) n se

Watch Video
image Watch Video
2
Se Ese Ni Ki Obirin Bi Omo Koto Lo Si Ile Oko Emi?

orisun

15/08/2017

281

Single Mother je nkan ti o je ajeji si asa ile yoruba. sugbon opo single mothers lo wa lawujo wa yala nipa iwakuwa tabi circumstances.

Watch Video
image Watch Video
2
Obi O Le Pase Lori Eni Ti Omo Fe Fe, Aye Ti Yato

orisun

14/08/2017

280

Marriage (igbeyawo) je igbese to se pataki ninu aye awon omo wa, ti o si se koko ninu asa ati ise ile yoruba. Fifowosi igbeyawo omo lati owo obi na se pataki

Watch Video
image Watch Video
4
Kini ki n se: Iya Oko Mi O Je Kin Gbadun Tori Mo Ti Bimo Ri

orisun

11/08/2017

300

E ba wa da si oro arabirin yii. Won fi iwe ranse si atokun wa Ibrahim Lori eto Ojuri, won so wipe iya oko awon o je ki awon gbafun ile oko awon tori wipe awon ti bi omo ri tele

Watch Video
image Watch Video
3
E Gbami: Oko Mi Ma N Na Mi To Ba Fe Bami Lajosepo

orisun

11/08/2017

204

Arabirin kan lo fi atejise yi ranse si atokun wa lori eto Ojuri, O so wipe gbogbo igba ti oko ohun ba fe ba ohun ni ajosepo ni o ma n na ohun

Watch Video
Ito suga Ito suga Watch Video
5
LILO OMO NI ILOKULO (CHILD ABUSE): OJURI

orisun

30/11/2016

210

Lori Eto Ojuri loni, eni-owo Adediwura Adeoye ati Wooli Adebayo Ayobami n soro lori eto omo'niyan [Human Rights].

Watch Video
image Watch Video
2
A MUST KNOW BEFORE YOU TIE THE KNOT (OJURI)

orisun

19/09/2016

207

Here is a program that deals with true life story happening to people which you can learn from. Here is an incident of a man who lured a lady into a polygamy marriage while masquerading himself as being single

Watch Video
image Watch Video
4
NURTW WORKERS VS BUS DRIVER IN IBADAN – OJURI

orisun

29/08/2016

163

It was a sad day three weeks ago in Ibadan, the capital of Oyo State when the workers of The National Union of Road Transport Workers engaged a bus driver in a chase which ended up in fatal accident killing all passengers except one survival

Watch Video
image Watch Video
3
EXPOSED!!! REASONS BUILDING COLLAPSES IN LAGOS (OJURI)

orisun

24/08/2016

139

In the video on Ojuri is a look at causes of building collapse in Nigeria with emphasis on collapse building in Lekki. Building construction is a high risk activity that must be effectively controlled by building owners and effectively regulated by the governm

Watch Video