OJUMO IRE

All Videos : 49  Video Posted

image Watch Video
Orisirisi Aisan Ti O Wa Ninu Enu Yato Si Oorun Enu

orisun

22/08/2017

436

Enu ni eya ara akoko ti on gba ounje ti o si n pese ito (saliva) ati ti awa eniyan fi n soro. Itoju enu je nkan ti o se pataki nitori aise itoju re ma n fa oorun si enu ti o si see muyangan ni awujo

Watch Video
image Watch Video
Se Orin (Music) Aye Atijo Leko Ninu Ju Ti igbalode lo?

orisun

11/08/2017

328

Music (orin) je ounje emi ti o ni ipa lati mu inu eniyan dun, ibaaje hip hop, apala, fuji, sanyan, ewi, juju atibeebeelo. Ni aye ode isnyin awon orin ti a n gbo yato si eyi ti won gbo ni aye atijo.

Watch Video
image Watch Video
Bi A Se Le Gba Lada Nipa Riran Eniyan Lo Hajj

orisun

09/08/2017

280

Hajj je okan ninu awon opo islam ti o si je oranyan fun gbogbo musulumi ti o ba ti ni agbara lati se. Riran omo iya wa ninu islam lo si hajj ni lada pupo

Watch Video
image Watch Video
Se Gbogbo Nkan To N Sele Ninu Ile Wa Lori Ero Ayelujara

orisun

04/08/2017

363

Ni opo igba ni a ma n ri fideo tabi aworan nipa bi igbe aiye awon eyan se n lo lori ero ayelujara. opo igba ni awon eniyan ma n fi gbogbo nkan ti o n sele ninu ile ati igbeyawo won sori ero ayelujara ti o si ti fa ede aiyede laarin ebi ati ara

Watch Video
image Watch Video
Bi A Se Le Dekun Lilo Ero Ayelujara Ni Ona Aito

orisun

04/08/2017

280

Ero ayelujara ni nkan ti gbogbo eniyan nlo ni gbogbo agbanlaiye yala okunrin, obirin tabi omode. Ni aye ode isinyi, orisirisi nkan lo wa lori ero ayelujara won yi yala facebook, instagram,twitter,youtube, snapchat atibeebeelo

Watch Video
image Watch Video
Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi

orisun

04/08/2017

324

Hajj sise je okan ninu awon opo ti o di islam mu ati ilana fun gbogbo musulumi.. Orisirisi nkan ni o diro mo lilo si hajj

Watch Video
NYSC NYSC Watch Video
PATAKI ETO ISINJOBA NYSC NI ILU NIGERIA

orisun

15/01/2017

247

Pataki eto isinjoba NYSC ni ilu Nigeria ko se kekere nitori pe, o ti fun awon odo laaye lati keko sii ni ilu ti won ko mo ri. Jide Morounfolu ati Ikeji won joko jiroro lori pataki ede ati asa ati bi imo itan se se pataki si eto eko ni ilu Nigeria

Watch Video
history pataki history pataki Watch Video
Pataki Imo Itan Ni Awon Ileewe Wa Laye Ode Oni

orisun

15/01/2017

422

Pataki Imo Itan laye ode oni ni awon ileewe wa. O se pataki lati moo wipe lai s itan, ojo iwaju enikeni yoo ni baibai. Jide Morounfolu ati Ikeji won joko jiroro lori pataki ede ati asa ati bi imo itan se se pataki si eto eko ni ilu Nigeria.

Watch Video
beads beads Watch Video
E KO BI A TI N SE IYUN LORI ETO EJI OWURO

orisun

30/12/2016

353

Oge sise lori eto wa ti ose yii n soro nipa bi a ti n se BEADs. Anfani ni eyi fun yin lati ko bead lofe.

Watch Video
Oge Sise Oge Sise Watch Video
Oge Sise: Itoju Awon Oun Ti A N Lo Si Ara Wa

orisun

21/12/2016

719

Oge Sise: Itoju Awon Oun Ti A N Lo Si Ara Wa Atokun wa, Torera ni eto Eji Owuro se alayi lori itoju awon oun ti a n lo si ara wa.

Watch Video