OJUMO IRE

All Videos : 49  Video Posted

image Watch Video
ILARA LO SO MI DI ALAPA KAN-SAM GLORIOUS

orisun

27/09/2017

489

Sam Glorious je elere itage christiani ti o ma n se ere theatre nipa eko olorun pelu erin ni awon ile ijosin kakaakiri. Ere theatre sam glorious farape iru eyi ti Alfa Sule ma n se. Sam Glorious ati Atabatubu ni won jo wa lori eto Ojumo Ire ti won si jo fi oro

Watch Video
image Watch Video
NKAN TI EX-PASTOR, ALH. OYEWOLE SO NIPA ITAN ANOBI IBRAHIM

orisun

26/09/2017

436

Ojumo Ire ti ose yi pelu Owo Adua soro nipa itan Anobi Ibrahim gegebi opo igbagbo fun awa onigbagbo islam ati christiaani. Lati yannana akori yi alejo wa Alhaji Oyewole ti won je pastor teleri ti gbogbo eeyan mo si Pst Matew Oyewole, ti won ti di musulumi fun

Watch Video
BI A SE LE FI EEDU WO ARUN ARA

orisun

11/09/2017

554

BI A SE LE FI EEDU WO ARUN ARA Charcoal ti a tun le pe ni Eedu ko n she fun didana nikan, o ni awon anfani pupo ti o tun ma n se, eyi ti anfani si ara je okan lara awon iwulo eedu… Lori eto Ojumo Ire, Adenike ati Olatorera yannana bi a Watch Video

image Watch Video
Se O Ye Ki Osere Tabi Akorin Gbe Igba Idibo?

orisun

08/09/2017

301

Opo osere ati awon ti won n ko orin ni won ti gbe igba ibo seyin ri. Awon bi 9ice, Funke Adeshiyan, Desmond Elliot atibeebeelo. Awon kan gbe igba ibo won si yege ti awon kan o si yege. Sugbon se o ye ki awon osere tabi olorin wa yi ki won maa gbe igba

Watch Video
image Watch Video
BI A SE LE YO LAALI KURO LOWO

orisun

07/09/2017

347

Laali je nkan ase ara looge ti o wa lati ilu india ti o fi wa di pe o wopo ni Nigeria paapaa julo ni ile hausa… Opo awon obirin isinyin ni won ma n feran lati se laali si owo tabi eekanna owo ati ese papa julo ni ojo igbeyawo… Bi oge laali se Watch Video

image Watch Video
KINI NKAN TI A N PE NI IGBAGBO?

orisun

31/08/2017

782

Igbagbo lai si ise, asan ni o. Kini nkan ti a n pe ni igbagbo? Tani o ye ki a fi igbagbo wa si odo re? Tani o ye ki a ni igbagbo ninu e? ba wo lo se ye ki igbagbo wa jin to? igba wo lo ye ki a ni igbagbo di? se eyin ni igbagbo ninu olohun?

Watch Video
image Watch Video
EWO BI ATABATUBU ATI OLORI SE N LU GANGAN

orisun

29/08/2017

437

Atabatubu ati Olori kemi ti tun de gegebi ise won lati ma mu yin larada lori eto Ojumo ire. Loteyi, atabatubu ati olori kemi di onilu ti won si korin si.

Watch Video
image Watch Video
EWO ITAN BI WON SE JU ANOBI IBRAHIM SI INU INA

orisun

29/08/2017

442

Anobi Ibrahim (peace be upon him) je baba gbogbo awon anobi olorun. Ni igba kan ninu igbese aye Anobi Ibrahim (peace be upon him) awon ara ilu ti o n waasu oro olorun fun won pete pemo lati ju sinu ina ki Allah

Watch Video
image Watch Video
TAANI ANOBI IBRAHIM, IRU EEYAN WO LO JE?

orisun

28/08/2017

338

Anobi Ibrahim ti awon elesin keji mo si Abraham je okan ninu awon anobi ti olorun yo nu si ti o si fi ara re han si. Opo eniyan o mo pe igbese aiye anobi ibrahim

Watch Video
image Watch Video
Nje O Dara Ki Eniyan Fi ISE Ijoba Sile Se ISE ORIN?

orisun

25/08/2017

358

lORI ETO OJUMO IRE PELU ATABATUBU ATI OLORI KEMI, WON GBE AKOLE PE SE O DARA KI ENIYAN FI ISE IJOBA SILE LATI SISE ORIN

Watch Video