Category - OJUMO IRE

BI A SE LE YO LAALI KURO LOWO

Laali je nkan ase ara looge ti o wa lati ilu india ti o fi wa di pe o wopo ni Nigeria paapaa julo ni ile hausa… Opo awon obirin isinyin ni won ma n feran lati se laali si owo tabi eekanna owo ati ese papa julo ni ojo igbeyawo… Bi oge laali se rewa to, o ma n pe ki o to kuro ni ara eyi ti...

KINI NKAN TI A N PE NI IGBAGBO?

Igbagbo lai si ise, asan ni o. Kini nkan ti a n pe ni igbagbo? Tani o ye ki a fi igbagbo wa si odo re? Tani o ye ki a ni igbagbo ninu e? ba wo lo se ye ki igbagbo wa jin to? igba wo lo ye ki a ni igbagbo di? se eyin ni igbagbo ninu olohun?

EWO ITAN BI WON SE JU ANOBI IBRAHIM SI INU INA

Anobi Ibrahim (peace be upon him) je baba gbogbo awon anobi olorun. Ni igba kan ninu igbese aye Anobi Ibrahim (peace be upon him) awon ara ilu ti o n waasu oro olorun fun won pete pemo lati ju sinu ina ki Allah

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.