OJU OJA

All Videos : 1  Video Posted

Oju Oja Oju Oja Watch Video
3
Oju Oja: Lile Oloja Kuro Ni Egbe Titi

orisun

21/12/2016

165

Lori Eto wa Oju Oja, Atokun wa Atabatubu ati Lara Olubo losi oju oja lati mo ero awon oloja lori bi awon ti ijoba fi ise ran lati le oloja kuro ni oju titi se n se won.

Watch Video