MILIKI EXPRESS

All Videos : 63  Video Posted

image Watch Video
BI AWON OBI SE N SE OKUNFA MOLESTATION

orisun

21/09/2017

385

Molestation iyen Fifowokan Eniyan lona aito ni akori eto lori Miliki Express pelu Torera ati Tope. Gbogbo wa lati gbo orisirisi iroyin nipa Fifowokan Eniyan lona aito iyen molestation, amoo ibeere wa ni wipe nje eyin mo awon ona orisirisi ti awon obi n gba se

Watch Video
image Watch Video
IDI TI AWON ALASE CITY PEOPLE AWARDS SE PIN AYEYE WON KELEKELE

orisun

20/09/2017

295

City People Awards je award ti o ma n fi gbeoriyin fun awon entertainers iba je olorin, osere, movie producers, directors ati awon ti owa ni eyin itage fun ise opolo ti won n se. City People Award ti o wa lati owo awon alase iwe idaraya (magazine) city people

Watch Video
image Watch Video
Pataki Idariji Ninu Irin Ajo Ife Laarin Okunrin Ati Obirin

orisun

15/09/2017

302

Forgiveness (idariji) ninu igbeyawo tabi ni aarin irin ajo ife okunrin ati obirin se pataki gan. Ti okan ninu awon okunrin ati obirin tabi tokotaye o ba ni emi idariji, igbati ija ba sele laarin won o ma nira ki irepo ati ife to danmoran wa ni aarin won.. Olat

Watch Video
image Watch Video
Anfani Kiko Makeup Lodo ASOJULOGE yato si Youtube

orisun

15/09/2017

247

Make Up sise yala fun ara eni tabi fun elomiran ti wopo ni ayika wa bayii. Opo obirin ni o ti ko bi won se n se makeup yala fun lilo araeni tabi gegebi ise owo. Ti won ba si bi won, won a ni awon ko ni owo asojuloge kan tabi ni ori ero Watch Video

image Watch Video
Igbese Akoko Ti O Ye Ka Gbe Fun Eto Ayeye IGBEYAWO

orisun

14/09/2017

475

Marriage (igbeyawo) je oun idunnu ati ayo ti gbogbo obi gba ni adura fun omo ati oun ti omo gan paapaa gba fun ara re. Won ni ti omode ba ti too loko, oye ko loko ni…. Nje ti omode ba ti se tan lati ni oko Igbeyawo, kini igbese akoko ti o ye ki Watch Video

Ipa Ti Osere Obirin N Ko Ninu Ere Lo N Fa Iwokuwo Won- Olajuwon Adewunmi

orisun

12/09/2017

216

Ni enu ojo meta yii, opo eniyan lo n soro nipa iwokuwo awon osere obirin wa ninu awon sinima agbelewo wa, ti awon osere gan ni oro kan tabi meji so lori oro naa. Osere Olajuwon Adewunmi ti o ti se opo ere agbelewo je alejo lori miliki express pelu bimbo ati ay

Watch Video
image Watch Video
Ijoba Orun Ko Fee, Mi O Le Ya TATTOO – Oyita

orisun

08/09/2017

267

Osere Oyita ni alejo wa lori Miliki Express Pelu Ayinke ati Bimbo ti won si soro nipa imnua ati iwokuwo awon osere obirin ni nollywood, storyline awon ere agbelewo nollywood ati idi ti awon story won fi ma n jo ara won. Lori eto, Ayinke bi Osere Oyita boya o l

Watch Video
image Watch Video
Mo Ti N Fi Ise Aderinposhonu Pa Owo Lati Ile Iwe- KOFFI

orisun

05/09/2017

261

Koffi je aderinposhonu agba ni orile ede nigeria. Ko wopo ninu awon aderinposhonu ki o si gbajumo di asiko yii. Ogbeni Koffi je alejo wa lori eto Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo won si ba wa soro nipa igba ti awon bere ise adeirinposhonu  ati bi won se d

Watch Video
image Watch Video
Ona Orisirisi Ti A Le Fi Style Natural Hair

orisun

05/09/2017

252

Oge sise ti ko ja ki a kan maa ko attachment sori tabi ki a ma pack irun wa si oju kan na ni ojoojumo. Oge ti o ti n wopo laarin awon odo obirin ati awon agbalagba gan ni Natural Hair. Awon ologe obirin isinyi ma n feran ki won maa gbe irun natural Watch Video

image Watch Video
Orin Ni Mo N Ko Kin To Ya Mo Ise Theatre- OYITA

orisun

05/09/2017

419

Oyita gegebi awon ololufe re se mo si je osere ere agbelewo ti o se fowo ro seyin ti o si ti wa ni idi ise yi fun igba die. won ni anfani lati wa si ori eto wa Miliki Express pelu ayinke ati bimbo won si bawa so oro lopo lopo. Won soro nipa Watch Video