MILIKI EXPRESS

All Videos : 63  Video Posted

image Watch Video
KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON

orisun

12/12/2017

401

KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON Lara Olubo Pelu awon alejo re soro nipa Ife laarin loko at i laya bi won ti se n gbe papo. Eyi ti o ka oju wa ninu awon nnkan ti won so ni nina Iyawo ti awon okunrin miran maa

Watch Video
image Watch Video
Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko

orisun

12/12/2017

547

Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko Lara Olubo ni Olootu eto wa loni, Won si fi asiko naa ba alejo won soro lori IGBEAYE OBINRIN LODEDE OKO. Nje Kini Eyin Naa Ro Nipa Bi Obinrin se n gbe Ile Oko. E wo fidio ti o wa loke yii ki e le ri Watch Video

image Watch Video
Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

orisun

12/12/2017

314

Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O Adari Ere ati ogbountarigi elere so wipe Oko Mercy Aigbe n tahun si oun lori ero ayelujara wipe ki oun fi Mercy sile. Iyalenu ni o je fun wa bi Lege miami se so wipe oun ko ni nnkankan pelu Oser

Watch Video
image Watch Video
Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

orisun

11/12/2017

411

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni Yetunde ObaNla pelu LARA OLUBO joko lori eto toni lati so isipaya ti o faa ti awon se yipada lati inu esin Musulumi si ti Kiriyo gege bi baba Yetunde Obanla se maa n pee. Omo Alhaji bi awon miran ti maa n

Watch Video
image Watch Video
AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON

orisun

05/10/2017

529

AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON OLORIN JAYWON ti aye mo ko awon orin bii This Year, Facebook Love, Joromi Jomi, Banuso ati beebeelo ni alejo wa lori Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo… O dahun ibeere ti o nii se pelu bi o se n ri im

Watch Video
image Watch Video
AWON ANFAANI TI MO TI JE NI IDI ISE THEATRE- YOMI FABIYI

orisun

05/10/2017

423

Yomi Fabiyi je osere ere theatre ti o odu ti o kin se aimo fun oloko, iyen tunmo si wipe ilumooka ni osere yomi Fabiyi…. Ogbeni Yomi Fabiyi tun je osere ti o tun mu adari ere mo gbogbo awon nkan ti o n se, Awon ere ti Yomi Fabiyi ti se ni Metomi, Ife

Watch Video
image Watch Video
Ko Pon Dandan Ki Awon Osere Fi Enu Ko ENu Ninu Ere Nollywood

orisun

04/10/2017

504

Ere sinima nollywood paapaa julo ere Yoruba wa ni awon igba ti awon osere naa ma fi enu ko enu ti won ba fe koi pa toko taya ninu awon ere naa… Lori eto Miliki Express Toyin ati Olayemi  ba alejo wa soro nipa akole yii, nkan ti o so wa ninu fidio yii, e

Watch Video
image Watch Video
ARTQUAKE TI WA PO LATI 1995- ADEX-ARTQUAKE

orisun

27/09/2017

266

Artquake ti n da wa laraya lati aye igba ti won ko awon ori ti o n mu wa jo bii Alanta, Abule Lawa ati beebeelo. Okan lara awon meji ti o n je Artquake ni Alejo wa lori eto Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo, won soro nipa ibere Artquake, awon orin orisirisi

Watch Video
image Watch Video
Odo Awon Alaabo Ara Ni Emi Yoo Ti Maa Se Ojo Ibi Mi – Jaywon

orisun

22/09/2017

324

Olorin Jaywon ti o se ojo ibi re ni osu die si isiyin so wipe oun kii se bi awon ilumooka to ku to je wipe ojo ibi won nikan lo maa n lo si odo awon omo alaabo ara lati ba won ya photo ti won ma gbe si ori ero abanidore instagram. o

Watch Video
image Watch Video
OLU JACOBS,SAHEED BALOGUN ATI AWON CELEB TO SE AJOYO NI SEPTEMBER

orisun

21/09/2017

249

CELEBRITIES Birthdays tabi ajoyo omiran kankan ti awon celebrities (ilu Mooka) wa ba se ma je nkan ti awa ololufe won maa n fe mo nipa re. Ni osu kesan odun yii (september,2017) awon ilu mooka repete se ajoyo orisirisi, awon eyi naa si la mu wa fun yin lori et

Watch Video