KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON

image
Description

KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON

Lara Olubo Pelu awon alejo re soro nipa Ife laarin loko at i laya bi won ti se n gbe papo. Eyi ti o ka oju wa ninu awon nnkan ti won so ni nina Iyawo ti awon okunrin miran maa n na eni ti won fe sile.

Ibeere naa jade wipe, Kilode Ti Awa Okunrin fi n Na Ayawa Wa. Beeni Eyin Obinrin, kini Idi ti oko yin fi maa n nayin?

E Wo fidio yii ki e ka nnkan ti Lara ati Alejo re ni lati so…E Wo Oke fun fidio naa.⇑⇑

Goodluck Jonathan Ba Wizkid Yo Lori Ami-Eye Tuntun MOBO

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *