Category - MILIKI EXPRESS

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni Yetunde ObaNla pelu LARA OLUBO joko lori eto toni lati so isipaya ti o faa ti awon se yipada lati inu esin Musulumi si ti Kiriyo gege bi baba Yetunde Obanla se maa n pee. Omo Alhaji bi awon miran ti maa n pe je Olokiki akorin ti awon...

AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON

AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON OLORIN JAYWON ti aye mo ko awon orin bii This Year, Facebook Love, Joromi Jomi, Banuso ati beebeelo ni alejo wa lori Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo… O dahun ibeere ti o nii se pelu bi o se n ri imisi fun awon orin ti o n ko...

AWON ANFAANI TI MO TI JE NI IDI ISE THEATRE- YOMI FABIYI

Yomi Fabiyi je osere ere theatre ti o odu ti o kin se aimo fun oloko, iyen tunmo si wipe ilumooka ni osere yomi Fabiyi…. Ogbeni Yomi Fabiyi tun je osere ti o tun mu adari ere mo gbogbo awon nkan ti o n se, Awon ere ti Yomi Fabiyi ti se ni Metomi, Ife Iyara Ikawe (Classroom Love) ati...

Ko Pon Dandan Ki Awon Osere Fi Enu Ko ENu Ninu Ere Nollywood

Ere sinima nollywood paapaa julo ere Yoruba wa ni awon igba ti awon osere naa ma fi enu ko enu ti won ba fe koi pa toko taya ninu awon ere naa… Lori eto Miliki Express Toyin ati Olayemi  ba alejo wa soro nipa akole yii, nkan ti o so wa ninu fidio yii, e woo.. E LE KA: Awon Osere Yoruba Ti...

ARTQUAKE TI WA PO LATI 1995- ADEX-ARTQUAKE

Artquake ti n da wa laraya lati aye igba ti won ko awon ori ti o n mu wa jo bii Alanta, Abule Lawa ati beebeelo. Okan lara awon meji ti o n je Artquake ni Alejo wa lori eto Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo, won soro nipa ibere Artquake, awon orin orisirisi ti Artquake ti Ko ati ipo ti...

Odo Awon Alaabo Ara Ni Emi Yoo Ti Maa Se Ojo Ibi Mi – Jaywon

Olorin Jaywon ti o se ojo ibi re ni osu die si isiyin so wipe oun kii se bi awon ilumooka to ku to je wipe ojo ibi won nikan lo maa n lo si odo awon omo alaabo ara lati ba won ya photo ti won ma gbe si ori ero abanidore instagram. o so wipe oun ma maa se ajoyo ojo ibi oun pelu awon alaabo...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.