Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Ona kakanfo Je Ni Ilu Oyo

image
Description

Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Onakakanfo Je Ni Ilu Oyo

Ileese Telifisan Orisun wa nibi ayeye Ifijoye ti won se ni Ilu Oyo fun Are Onakakanfo tuntun ni awujo awon omo Yoruba ni Ilu Nigeria ati kaakakiri gbogbo agbaye ti awon omo Nigeria wa.

Pelu Ijo ati ayo ni won fi yan Ogbeni Gani Adams si ipo naa.

E wo fidio ti o wa loke pata-pata yii ki e le wo bi o ti lo:

⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑⇑

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *