ISEMBAYE

All Videos : 6  Video Posted

image Watch Video
Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Ona kakanfo Je Ni Ilu Oyo

orisun

31/05/2018

495

Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Onakakanfo Je Ni Ilu Oyo Ileese Telifisan Orisun wa nibi ayeye Ifijoye ti won se ni Ilu Oyo fun Are Onakakanfo tuntun ni awujo awon omo Yoruba ni Ilu Nigeria ati kaakakiri gbogbo agbaye ti awon omo Nigeria wa. Pelu Ijo ati ayo

Watch Video
isese-day-osun-osogbo-orisun isese-day-osun-osogbo-orisun Watch Video
Aregbesola Pe August 21 Ni Isese Day

orisun

18/08/2017

410

Ijoba Ipinle Osun ti pe ojo aje, august 21, 2017 ni public holiday lati se ajoyo Ojo Isese ti won ma n se ni odoodun. Isese day je ojo ti won ma n gba isinmi fun awon elesin isembaye

Watch Video
image Watch Video
Orun Ni Gbogbo Eegun Ti Wa, Oosa si ni won

orisun

11/08/2017

449

Nibo ni eegun ti wa? Ta lo da won si aye? Ni bo ni won ti jeyo? Kini Ipinlese awon eegun? Opo awon asa kan kan ti sonu sugbon sise odun eegun

Watch Video
image Watch Video
Bi Won Se Se Ayeye Odun Eegun Ni Ilu Ode Remo

orisun

11/08/2017

527

egun je okan gboogi lara awon asa ati ise  ile yoruba. Ni aipe yi ni won se ayeye odun eegun ni ilu ode remo ti atokun eto isembaye lo mu wa fun eyin ololufe re....

Watch Video
image Watch Video
#Isembaye: Eegun Ile Ati Idi Ti A Fi N Bo Eegun

orisun

10/08/2017

582

Yoruba je eya ti o kun fun orisirisi ise ati asa ti o to won sona ninu gbogbo nkan ti won n se lati aye ba aye ti won si n fi le omo lowo lati ori generation kan si ekeji.

Watch Video
ISEMBAYE ISEMBAYE Watch Video
Odun Ijesu Ni Ilu Ogidi Lori Eto Isembaye

orisun

04/01/2017

483

Odun Ijesu je odun ti a ma n se ni odoodun lati fi inu didun han pe Isu titun jade. Orisun je Telifisan ti o n ko omo ni ede ati asa pelu ise.

Watch Video