IROYIN LORI ORISUN

All Videos : 31  Video Posted

image Watch Video
2
Bi Won Se N Se Eto Igbeyawo Ni Ile Yoruba

orisun

22/09/2017

599

Marriage (igbeyawo) ni ile yoruba,  je nkan pataki; o je nkan iwuri.MArriage (igbeyawo) ti won n se ni aye atijo ti yato si bi won ti n se ni aye isin leyi ti o tii di aye olaju… Bawo ni won se n se ni aye atijo? Kini awon elo ti won lo? E TUN Watch Video

kwara-mysterious-disease-orisun kwara-mysterious-disease-orisun Watch Video
3
Ko Si Aisan Kayefi Kankan Ni Kwara-Commissioner

orisun

18/08/2017

188

Ijoba Kwara ti so fun gbogbo ara ilu won wipe ko si aisan kayefi kankan ni ipinle na, gegebi iroyin lati owo commissioner fun ilera,Dr Atolagbe Alege. Dr Alege so eyi di mimo ni ilorin nigba ti o n soro nipa iroyin ti on kan kakaakiri nipa aisan kayefi kan ni

Watch Video
image Watch Video
1
Lara Olubo, Ayinke Kujore ati Oga Orisun Ki Ijo Mo Le

orisun

10/08/2017

165

Orisun ni agba, awa ni Oga. Ki ni idi ti a fi n so be? A ma n wi be nitori pe bi a ti n se nkan wa o yato si bi gbogbo ile ise se n se nkan won.

Watch Video
image Watch Video
2
Owo Olopa Te Onisenlaabi Ti O Wa Nidi Ajaale Ilu Sango Ota

orisun

10/08/2017

286

Olopa orile ede nigeria o se ma ri idi Ajaale ni ilu wa latari wipe gbogbo igba ni owo won n te orisirisi onisenlaibi ti won si n mu won lo si ibi ti ajale

Watch Video
image Watch Video
1
Didekun Iwokuwo Awon Osere, Ise NFVCB Ni -Femi Adebayo

orisun

09/08/2017

299

Nollywood ti gba opo ibawi lori Iwokuwo awon osere obirin won ninu sinima agbelewo won, ti opo eyan si ti so orisirisi oro lori nkan ti won le se lati dekun iwa yi.

Watch Video
image Watch Video
1
E So Sinima Ti Omo Yin N Wo- Osere Hassan Goriola Si Awon Obi

orisun

03/08/2017

256

Osere sinima agbelewo, Ogbeni Hassan Goriola ti fi idi e mule peki awon obi maa so ohun ti awon omo won nwo lori amumaworan...

Watch Video
Awon-omo-ile-iwe-psmb-children Awon-omo-ile-iwe-psmb-children Watch Video
2
Ni Ojoru Ikilo Jade Fun Awon Obi Lori Awon Omo Won Ni Ile-Iwe

orisun

21/07/2017

317

Ni ojo ojoru awon igbimo egbe Post Primary School Management Board

Watch Video
evans-CRIMINAL-kidnapper-trend-orisun evans-CRIMINAL-kidnapper-trend-orisun Watch Video
2
Egbon Ogbologbo Ajinigbe Evans Ti Fi Asiri Miran Han O

orisun

20/06/2017

258

Ogbeni Evans ti aye n so wipe ki won da sile leyin ti won ti mu fun esun ijinigbe ati opolopo ise ibi ti o ti gbe se si wa lewon. Lana ti o je Ojo Aje, ni a rii gbo wipe Otito miran ti jade nipa Isele naa.

Watch Video
image Watch Video
1
Awon Boko Haram Meji Ti Sanku Leyin Igbiyanju Ati Pa Ilu Kan Run

orisun

09/04/2017

341

Ajo Olopa ti ilu Maiduguri so fun awon oniroyin ni Oni Satide wipe awon obinrin ti a fura si wipe won je omo iko Boko haram sanku nigbati eyokan ninu won yin Ado oloro (IED) mo ara re.

Watch Video
dino-melaye-orisuntv dino-melaye-orisuntv Watch Video
2
DINO MELAYE Ti Lo Gba Satifikeeti Re Ni ABU Zaria Ooo. E wo Iye Eniyan To Tu Jade

orisun

08/04/2017

250

Sineto Ile igbimo asofin-agba, Ogbeni Sineto Dino Melaye ti o soju Ipin;e kogi labe asia egbe APC ti lo gba Iwe Eri ni Ilu Zaria ni ile iwe giga Ahmadu Bello University, Awon Aworan yii fihan bi awon ololufe Sineto Dino ti feran re to. Melaye who was recently

Watch Video
fayemi-fayose-orisun-orisuntv fayemi-fayose-orisun-orisuntv Watch Video
2
Ala Re Ko Le Se O, Fayose So Fun Fayemi Bee

orisun

04/04/2017

285

Gomina Ayodele Fayose ti Ilu Ekiti ti fi esun kan eni ti o gba ijoba lowo re, Ogbeni Kayode Fayemi pe o n ko'na ote lati gba ona eyin lati pada di Gomina Ilu naa latiGomina Ayodele Fayose ti Ilu Ekiti ti fi esun kan eni ti o gba ijoba lowo re, Ogbeni Kayode Fa

Watch Video
Dino-Melaye-orisun-orisuntv Dino-Melaye-orisun-orisuntv Watch Video
3
Ti Oo Ba Be Saraki, Wahala N Bo O – DINO MELAYE

orisun

01/04/2017

230

Ogbeni Dino Melaye ni Amoran fun sineto Ali Ndume bi yoo ti se se Idaniduro lenu ise ti won fun-un; O so wipe, ko ba yara bebe ki o to pe ju.

Watch Video

No more postsLoading posts ...Load More

No more postsLoading posts ...Load More