#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ MỌ AMI ORI ỌRỌ YII? “Abetilukara Bi Ajere” – OBAT

OBAT-OBATAYO-ORISUN-ATABATUBU
Description

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ MỌ AMI ORI ỌRỌ YII? “Abetilukara Bi Ajere” – OBAT

Lori eto t’oni, Atabatubu bi alejo rẹ ni abala ami-ori-ọrọ nipa ami ori ọrọ kan ti awọn eniyan maa n fi n ki ọlọrun. Alejo rẹ OBATAYO ti gbogbo aye n pe ni OBAT ni ẹni ti wọn sọ fun ki o fi ami si ori awọn ọrọ naa.

Njẹ ẹyin naa mọ ami ti o yẹ ki o wa lori ọrọ naa?

Ẹ woo boya OBAT ri esi ti o yanranti fọ si ibeere naa:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *