#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii

ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION
Description

#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii

Gẹgẹ bi ẹyin ololufẹ Atabatubu ti mọ olorin naa, amuludun ni; bẹẹni akọrin ni loju agbo. Pẹlu ijo, ọyaya ati orin ni o fi pari Eto Baba Eto lọsẹ yii. Eyi jẹ ara ọtọ ju t’atẹyin wa lọ.

Oun ati awọn ọmọ ẹgbẹ rẹ ni wọn ṣe fanran ti ẹ o wo laipẹ.

Ẹ wo fidio ti o wa ni isalẹ yii fun LIVE BAND PERFORMANCE naa:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *