Category - ETO BABA ETO

Bi Trinity Se Waye Ninu Oruko KUNLE-TRINITY

Lori eto wa Eto baba eto loni, Alejo wa Kunle Trinity pelu Atabatubu soro nipa nnkan ti o bi Oruko ti o n je. 

O bere pelu bi o se n je Metalokan ati bi awon elegbe re ni kekere se maa n pe ni metalokan, nitori bi o se maa n yi orin kan si ona meta nipase awada.

opo

Eto Baba Eto: Ero Olori Awon Opo

Ni ori Eto Baba Eto ni ose yii, a o soro olori awon opo (Widows). Kilode ti afi gbodo se itoju awon opo? Lara Olubo ni atokun pelu Olusoagutan, mummy wa, Mrs Olajide. E ma ba wa kalo.

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.