BO SE NLO

All Videos : 33  Video Posted

image Watch Video
3
Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

orisun

21/03/2018

418

Eku dede asiko yii eyin ololufe Orisun. Lori eto #Bosenlo t’oni ni a ti soro nipa ibasepo okunrin ati obirin ninu ile paapajulo eni ti o ye ki o se olori ile. Lara nnkan ti enikan so ni wipe O dara ki okunrin je olori nitori wipe lati inu itan wa ni a ti

Watch Video
image Watch Video
3
Christian Ati Aisan Ogbe Inu (ULCER) Lori Bosenlo HEALTH

orisun

12/12/2017

381

Christian Ati Aisan Ogbe Inu Lori Bosenlo Gegebii Kristieni, Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se si Watch Video

image Watch Video
1
AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII

orisun

12/12/2017

302

AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se Watch Video

Alex-Iwobi-and-Kelechi-Iheanacho-orisun Alex-Iwobi-and-Kelechi-Iheanacho-orisun Watch Video
5
NIGERIA GBODO NA ZAMBIA TABI GBA DRAW NI WORLD CUP QUALIFIER

orisun

03/10/2017

358

Super Eagles ti ilu Nigeria ma gba boolu idije ese keta (3rd round) world cup qualifier pelu egbe agbaboolu Chipolopolo ti ilu zambia ni papa isere (stadium) Uyo ni October 7th, 2017 ni dede ago marun. Awon atokun wa lori eto Bosenlo Sports ri si oro idije boo

Watch Video
foods-good-for-stomach-ulcer-orisun foods-good-for-stomach-ulcer-orisun Watch Video
4
IRU OUNJE TO DA FUN ENI T’ONI STOMACH ULCER

orisun

03/10/2017

345

Stomach Ulcer je arun ti o ma je yo ni inu ikun omo eniyan ti a ko ba se awon nkan ti o ye ki a se. Ni opo igba ni awon ti o ba ni Stomach Ulcer o kin mo iru ounje ti o ye ki won ma je, Opo igbe ni won ma Watch Video

image Watch Video
6
GBOGBO NKAN TI O YE KI E MO NIPA ARUN MEASLES

orisun

26/09/2017

297

MEASLES je arun ti o kan omode ati agbalagba, measles je arun ti o ma n fa iku ti a ko ba tete fun ni itoju ti o ye, Kini awon nkan ti o ye ki e mo nipa arun measles yii ati wipe ki lo n pe ni arun measles… e wo fidio ….. Watch Video

image Watch Video
4
BI A SE LE SE ITOJU OMO TO BA NI MEASLES

orisun

25/09/2017

528

MEASLES je okan lara awon arun buruku ti o ma n se okunfa opolopo iku omode ati agbalagba ni orile ede Nigeria. Awon ti o ma n kan agbake Arun Measles yi ma n ko lati ofurufuru (air) latari iko (cough) ati sinsin (sneeze) lati odo awon ti o ti ni tele. Ti eeya

Watch Video
image Watch Video
5
“Iku Awon Obi Mi, O je Ki n ka iwe siwaju”-Okiki Afolayan

orisun

20/09/2017

291

Movie Director to pe oju osuwon ni Ogbeni Okiki Afolayan je I won ba n soro nipa didari ere agbelewo ni eka Yoruba nollywood ni Nigeria. Ogbeni Okiki Afolayan je alejo wa lori eto Bosenlo pelu atokun wa Bimbo Ojuoge, won si soro niap iro eeyan ti Okiki Afolaya

Watch Video
image Watch Video
1
Awon Orisirisi Nkan Ti O N Fa LASSA Fever

orisun

13/09/2017

242

Lassa Fever je arun kan ti o gba ode kan ni orileeded Nigeria… Ni eto to lo, a so nipa nkan ti o n je Lassa Fever, Ni ori eto eleyi, A ma yannana Awon Orisirisi Nkan ti o n fa Lassa Fever lori eto Bosenlo pelu Sekinat Raji ati Alejo re….   E T

Watch Video
image Watch Video
3
Ewu Ti O Wa Ninu Ki A Maa Lodi Si Ofin OJU POPO

orisun

12/09/2017

231

Traffic Laws iyen Ofin Oju Popo se pataki ni gbogbo ona oju popo wa nitori ti o basi awon ofin yi, opo nkan ni o ma ti baje ti o ma je ki oju popo wa ma safe fun wa lati lo… Ijoba si ti se awon ofin yi lati mu popo wa safe fun

Watch Video
image Watch Video
1
Gbogbo Nkan Ti O Ye Ki E Mo Nipa Iba LASAA

orisun

12/09/2017

192

Lassa Fever je aisan ti o ti n fe ma wopo ni awujo ni isinyi. Iwadi fi ye wa wipe eni ti o ba ti ni aarun lassa o ki ni symptom kan kan bee ti o ami kankan ba je yo yoo je bi fever, weakness, headaches, vomiting, ati muscle pains. Kini Lassa Fever? Ki

Watch Video
image Watch Video
1
ONA ORISIRISI TI A N GBA PADANU OMI NI AGO ARA WA

orisun

05/09/2017

199

Omi(Body Fluid) je ara awon nnkan ti o je ki ara maa je ara. Ti ko ba si Eje ati omi ni ara omo eniyan, a ko le so wipe Eniyan ni wa. Loni lori Eto wa Bosenlo ni abala Ilera ni Atokun eto wa arabinrin Sekinat Raji ti soro nipa awon ona pataki ti Watch Video

No more postsLoading posts ...Load More

No more postsLoading posts ...Load More