Featured Videos

SHOWS

All Videos : 225  Video Posted

image Watch Video
3
Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Ona kakanfo Je Ni Ilu Oyo

orisun

31/05/2018

50

Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Onakakanfo Je Ni Ilu Oyo Ileese Telifisan Orisun wa nibi ayeye Ifijoye ti won se ni Ilu Oyo fun Are Onakakanfo tuntun ni awujo awon omo Yoruba ni Ilu Nigeria ati kaakakiri gbogbo agbaye ti awon omo Nigeria wa. Pelu Ijo ati ayo

Watch Video
image Watch Video
2
Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

orisun

21/03/2018

63

Eku dede asiko yii eyin ololufe Orisun. Lori eto #Bosenlo t’oni ni a ti soro nipa ibasepo okunrin ati obirin ninu ile paapajulo eni ti o ye ki o se olori ile. Lara nnkan ti enikan so ni wipe O dara ki okunrin je olori nitori wipe lati inu itan wa ni a ti

Watch Video
image Watch Video
3
NJE O Dara Ki A Maa Ni Emi IDariji Ninu Igbeyawo?

orisun

19/12/2017

43

NJE O Dara Ki A Maa Ni Emi IDariji Ninu Igbeyawo? Olatorera ati akegbe re Tope ni o n jiroro lori pataki Idariji laarin loko-laya ati nnkan ti o maa n fa Aini idariji. Gege bi a ti mo wipe, IFE ni akoja ofin, lai si ife, ko le si idariji-ese. Beeni o pon danda

Watch Video
image Watch Video
2
Idi Ti EMI IDARIJI Ko Wopo Laarin Ololufe Meji

orisun

13/12/2017

43

Idi Ti EMI IDARIJI Ko Wopo Laarin Ololufe Meji Lori Eto Miliki Express, Olatorera ati akegbe re Tope ni o n jiroro lori pataki Idariji laarin loko-laya ati nnkan ti o maa n fa Aini idariji. KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON E wo fidio yii ki

Watch Video
image Watch Video
3
#OJURI: Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

orisun

12/12/2017

32

Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju? Lori Eto Ojuri loni, Aralomo presenter bere lowo alejo re nipa awon nnkan ti awon omo le se lati fi ja fun eto won lati owo obi won. Bi awon omode se ni eto lati gba itoju gidi, aralomo bere nipa<

Watch Video
KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON

orisun

12/12/2017

59

KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON Lara Olubo Pelu awon alejo re soro nipa Ife laarin loko at i laya bi won ti se n gbe papo. Eyi ti o ka oju wa ninu awon nnkan ti won so ni nina Iyawo ti awon okunrin miran maa

Watch Video
image Watch Video
2
Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko

orisun

12/12/2017

75

Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko Lara Olubo ni Olootu eto wa loni, Won si fi asiko naa ba alejo won soro lori IGBEAYE OBINRIN LODEDE OKO. Nje Kini Eyin Naa Ro Nipa Bi Obinrin se n gbe Ile Oko. E wo fidio ti o wa loke yii ki e le ri Watch Video

image Watch Video
2
AWON ILUMOOKA TI O MAA N FI OWO OLA GBA AWON Ti O N BO LONA LOJU

orisun

12/12/2017

48

AWON ILUMOOKA TI O MAA N FI OWO OLA GBA AWON Ti O N BO LONA LOJU Civilized Omobadan pelu akegbe re, MC ABBEY joko lati soro lori bi won ti n fowo ola gbaAwon olorin, awon osere ti won n fi orin olorin, ere elere ati awon ti o n se ohun atinuda ti Watch Video

image Watch Video
4
Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

orisun

12/12/2017

30

Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O Adari Ere ati ogbountarigi elere so wipe Oko Mercy Aigbe n tahun si oun lori ero ayelujara wipe ki oun fi Mercy sile. Iyalenu ni o je fun wa bi Lege miami se so wipe oun ko ni nnkankan pelu Oser

Watch Video
image Watch Video
1
Christian Ati Aisan Ogbe Inu (ULCER) Lori Bosenlo HEALTH

orisun

12/12/2017

57

Christian Ati Aisan Ogbe Inu Lori Bosenlo Gegebii Kristieni, Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se si Watch Video

image Watch Video
1
AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII

orisun

12/12/2017

48

AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se Watch Video

image Watch Video
3
Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

orisun

11/12/2017

41

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni Yetunde ObaNla pelu LARA OLUBO joko lori eto toni lati so isipaya ti o faa ti awon se yipada lati inu esin Musulumi si ti Kiriyo gege bi baba Yetunde Obanla se maa n pee. Omo Alhaji bi awon miran ti maa n

Watch Video

No more postsLoading posts ...Load More

No more postsLoading posts ...Load More