Category - Politics

atiku-ABUBAKAR-ORISUN

Atiku Abubakar Ka Awon Ile Ise Ti O Je Ti E Ni Nigeria

Ni odun 2014, Igbakeji aare teleteleri, Atiku Abubakar so wipe oun mop e oun ni oun pese ise ju fun awon eeyan ni Nigeria yi. O so eleyi lori ero abanidore twitter re  @atiku nigba ti o n soro nipa awon odo orile ede yi ati pi pese ise fun odo ni Nigeria. “As an individual, I believe my...

E Wo Bi Bukola Saraki Se Ki Iyawo re Toyin Ku ojo ibi

Ni ori ero abanidore Twitter, Senate President Bukola Saraki se ajoyo pelu aya re toyin ti o pe omo odun meta le l’aadota ni oni. SAraki ko wipe; “Happy Birthday to my dear wife, best friend and extraordinary mother of our children! @ToyinSaraki, we love you dearly!” Toyin...

fayose-orisun

Fayose Fa Olusola Eleka Sile Gege Bi Oluropo Fun Ipo Gomina

Gomina ipinle ekiti, Ayodele Fayose ti fi ountelu Professor Kolapo Olusola Eleka gege bi oluropo e fun eto idibo ti o ma wa ye ni ekiti. Sunshine Anifowoshe, ti o je PA si gomina Fayose lo so eleyi di mimo ni ori ero abanidore facebook e.  Professor Kolapo Olusola Eleka ni igbakeji gomina...

EFCC-Operatives-ORISUN

Awon Agba Oloselu Ti EFCC N Se Iwadi Won Fun Iwa Ibaje

Ajo Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) si n se iwadi awon case kan ti o kana won bi oloselu ogorun (100) ati awon onise ijoba. Ninu iwadi ti o se jade, iwe kan ti o ni oruko awon case ti efcc n se iwadi won lowo ti jade,won si ti fi iwe na ranse si Attorney General of the...

Amosun fun Arabirin ti o bimo si Ojude Oba ni N100K

Amosun fun Arabirin ti o bimo si Ojude Oba ni N100K

Mrs Abibat Ayanlola, 32, ti o bi omo obirin ni igba ti won n se ojude oba festival ni ojo Sunday ni ijebu ode ti gba owo ti o ku si of N100,000 lati owo Gomina ipinle Ogun, Ibikunle Amosun Arabirin Ayanlola, gba ebun owo na lati owo commissioner fun eto ilera Dr Babatunde Ipaye ni igbati...

APC-BUHARI_PDP-

PDP Ro Buhari Ki O Kede Ipe Pajawiri Ni Ipinle Imo

Awon Omo Egbe PDP ti ipinle Imo ti ke pea are buhari lati kede ipe pajawiri ni ipinle imo. Eyi n waye leyin ti iroyin kan pe opolopo eeyan ni awon agbofinro pa ni ipinle naa ni ojo eti Saturday August 26, 2017 nigbati won se ifehonu han lori wiwo oja eke onunwa. Agbenuso fun pdp ni ipnile...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.