#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE

orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi
Description

#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE

Lọse yii, awọn atọkun eto wa gbe awọn iroyin pataki wa si eti igbọ wa lori gbogbo ohun ti o n lọ ninu sinima ati awọn oṣere. Yatọ si iroyin, wọn sọrọ lori awọn sinima miran ti o ṣẹṣẹ jade fun iworan ẹyin ololufẹ ileeṣẹ Orisun.

Ẹ wo fidio ti o wa ni isalẹ yii fun awọn iroyin naa ati nnkan miran ti ẹ o gbadun.

PRESENTER: ỌLAYẸMI ATI OLUWATOYIN OKI

PROGRAMME: MILIKI EXPRESS

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *