Local

All Videos : 44  Video Posted

Ooni-IFE-ORISUN Ooni-IFE-ORISUN Watch Video
1
Ooni Wo Igbale fun Ayeye Olojo Festival

orisun

26/09/2017

245

Awon ara ilu ile ife n retia won ajoji ti won ma wow a si ilu won fun ayeye olojo festival ti odun yii ti o ma waye ni Saturday to n bo. Ooni ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, so eleyi di mimo ni irole ojo Sunday ni  ile ife kete ki o to wo  igbale Watch Video

well-orisun well-orisun Watch Video
2
Aye Le O!!! Arabirin Yi So Omo Orogun Re Mejeeji Sinu Konga

orisun

15/09/2017

187

Owo sikun awon Olopa ni Nassarawa tit e iyawo ile (20) ti o n je Aisha Isah nitoripe o so awon omo orogun re meji sinu konga nitori edeaiyede ti o ni pelu iya awon omo naa… Agbenuso fun awon Olopa,  DSP Kennedy Idirisu, so nibi iforowanilenuwo pe owo won te

Watch Video
Lagos-Under-Bridge-orisun Lagos-Under-Bridge-orisun Watch Video
1
Ijoba Eko Setan Lati Palemo Abe Bridge Ojuelegba ati Ikeja

orisun

12/09/2017

199

Lati tun gbogbo awon idiko ti o wa ninu ipinle eko se, ijoba ipinle eko ti da ajo kan sile lati ri wipe awon idiko ti o leto ki o wa ni abe bridge ojuelegba ati ikeja poora. Alaga ajo yi, Olayinka Egbeyemi, so wipe ajo na ma bere si mu ise won ni sie Watch Video

Nasir-El-Rufai-orisun Nasir-El-Rufai-orisun Watch Video
1
“Mo Gbadura Ki Epo Robi  Nigeria Gbe” –E l Rufai

orisun

11/09/2017

142

Gomina Ipinle Kaduna, Nasir El-Rufai ti so wipe oun fe ki epo robi Nigeria ki o gbe, ti o sip e epo naa ni as “easy money”. O so wipe owo nla ti won n pa lati ori epo ni idi ti ijoba ilu Nigeria o se se nkan titun . O so eleyi ni Watch Video

fayose-orisun fayose-orisun Watch Video
1
Fayose Fa Olusola Eleka Sile Gege Bi Oluropo Fun Ipo Gomina

orisun

06/09/2017

194

Gomina ipinle ekiti, Ayodele Fayose ti fi ountelu Professor Kolapo Olusola Eleka gege bi oluropo e fun eto idibo ti o ma wa ye ni ekiti. Sunshine Anifowoshe, ti o je PA si gomina Fayose lo so eleyi di mimo ni ori ero abanidore facebook e.  Professor Kolapo Ol

Watch Video
dino melaye-dino-orisun-melaye-disgraced london dino melaye-dino-orisun-melaye-disgraced london Watch Video
2
Awon Omo Nigeria Fi Sineto Dino Melaye Se Yeye Ni Ilu Oyinbo

orisun

30/08/2017

304

Fidio kan se afihan awon omo Nigeria t’o n gbe ni ilu oba, ti won fi Sinato Dino Melaye ti o je asoju agbegbe awon sinato se yeye nibi ayeye kan ni ilu oyinbo.

Watch Video
ooni-of-ife-olori-wuraola-orisun ooni-of-ife-olori-wuraola-orisun Watch Video
1
Emi Ati Ooni Ko Fe Ara Wa Mo – Olori Wuraola

orisun

30/08/2017

249

Iyawo teletele ri ti ooni ife, Olori Wuraola ti jade lati so wipe oun ati ooni o si papo mo, pe igeyawo ti o wa laarin oun ati ooni ife oba adeyeye enitan ogunwusi ojaja II ti fiorisopon

Watch Video
Aisha-Buhari-orisun Aisha-Buhari-orisun Watch Video
3
Aya Aare Aisha Buhari Lo Mecca

orisun

28/08/2017

236

Aya aare orileede Nigeria, aisha buhari ti lo si mecca, Saudi Arabia ni ojo aje  Monday, August 28, 2017 lati ko pa ninu hajj odun yii

Watch Video
RAMS-eid-kabir-orisun RAMS-eid-kabir-orisun Watch Video
1
Ijoba Osun Pese Eran 648 Fun Tita Fun Odun Ileya

orisun

28/08/2017

239

Ijoba ipinle osun ti pinu lati pese eran 648 fun odun ileya ti o n bo lona. Eton a ti won pe ni 'O'RAM pelu ajosepolati owo Selema Oloba Ranch, Iwo ti sin eran bolojo ni aarin osu meji.

Watch Video
ileya-day-orisun ileya-day-orisun Watch Video
2
Sultan Sokoto Kede September 1st Gege Bi Ojo Ileya

orisun

23/08/2017

310

Sultan ilu Sokoto ati Alaga Nigerian Supreme Council for Islamic Affairs, Alhaji Sa’ad Abubakar,ti kede pe ojo jimoh September 1, 2017 ni ojo Ileya

Watch Video
Adeleke-amosun-orisun-tv Adeleke-amosun-orisun-tv Watch Video
2
Amosun Di Oju Ona Ki Awon Eniyan Ma Ri Oku Sineto Adeleke

orisun

24/04/2017

390

Gomina Akoko ti yoo se Gomina ipinle Osun ri ti o si je Sineto ni Ilu naa.. Sineto Isiaka Adeleke ti o ku ni aaro Ojo sunday April 23, 2017 ni ile-iwosan aladani kan ni Ilu osogbo leyin ti o ti ree fun igba die ni won sin ninu ekun oun ipayinkeke.

Watch Video
buhari-el-rufai-20199-inec buhari-el-rufai-20199-inec Watch Video
3
Wahala Yoo Sele Ti Buhari Ko Ba Je Aare Leekeji Ni 2019

orisun

15/04/2017

357

Aare Orile Ede yii, Mohammadu Buhari gbodo duro fun Idibo ti o n bo ni Odun 2019 bibeeko, gegede a gbina, kedere a bee wo; okan ninu awon ore re lo so bee ti o je gomina ipinle Kaduna ti oruko re n je Nasir El-Rufai.

Watch Video

No more postsLoading posts ...Load More

No more postsLoading posts ...Load More