Category - Entertainment News

equitorial-guinea-orisun

FIFA Yo Equitorial Guinea Kuro Ni 2019 Women Wrold Cup

Ajo FIFA ti yo Equitorial guinea kuro ni ibi idije 2019 world cup ni France nitoriwipe won ko agbaboolu mewa (10) ti o toju osunwon pelu iwe ayederu.Awon agbaboolu ko pa ninu idije Qualifier ni 2016 olympics fun awon obirin ni Brazil. E TUN LE KA:Bi Mo Se Bori Lilo Ogun Oloro Ati Irewesi...

Tiwa-Savage-and-Tee-billz-orisun

NKAN TI AWON EEYAN NSO NIPA ORO TI TIWA SAVAGE SO

ILUMOOKA TIWA SAVAGE TI SO ORO NIPA NKAN TI O RO LORI GENDER DISCRIMINATION. O SO ELEYI NI IBI IFOROWANILENUWO PELU ASORO LORI ERO RADIO BEATFM Toolz oniru lori eto re The Midday Show nigba ti won bi leere nipa oro naa. Tiwa savage so wipe obirin ni gbogbo ibi ma n tiraka ju awon okunrin...

femi-adebayo-orisun

Femi Adebayo Setan Lati Na 25m fun Ere Return Of Jelili

Osere Nollywood ati Omo Osere agba Adebayo Salami iyen Femi Adebayo ti o n ya ise ere meji kan lowo fun odun yii ti soro siwaju si lori ere re ti o n bo lona ti o pe ni Return Of Jelili; eyi ti o je ekeji ere gbajumo re Jelili Oniso. Femi Adebayo naa ti o so wipe oun ti setan lati darapo...

antar-laniyan-orisun

Araosan Lo Ba Mi De Nu Ko Iyawo Mi- Antar Laniyan

Ninu industry ere Yoruba, Antar Laniyan je oruko nla ti gbogbo eeyan fe diro mo. Antar Laniyan je ogbontarigi osere ti gbogbo awon adari ere si n fe ki o ma wa ninu ere won ni gbogbo igba nitori bi ose ma n se daadaa ninu ipa ti won ba fun. Looto, Ipinle osun ni idile oba ni Antar Laniyan...

mercy-aigbe-orisun

“E Ma Ra Aiyederu Ise Wa”- Mercy Aigbe

Osere Mercy Aigbe fi aworan ibi ti o ti sese si ori ero abanidore instagram re nibi ti won ti n se ere tuntun re “77 bullets”… O ko wipe; ‘Just got this injury on set, filming my new movie 77 BULLETS. We put in a lot of hardwork making these movies. Please support...

aisha-abimbola-orisun

Idi Ti Awon Adigunjale Se Feran Mi- Osere Aisha Abimbola

Osere aish abimbola ti gbogbo eeyan mo si omoge campus se iforowanilenuwo kan laipe yi pelu iwe iroyin the sun, o si soro nipa ise ere ti on se, igbeyawo re ati beebee lo… E kaa die ninu iforowanilenuwo naa bayii>>> Can you tell us how you came into acting? I came into‎ acting...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.