Category - News

Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc

Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Aare Ile-igbimo Asofin Sile

Won ti fi awon idi ti Saraki fi gbodo fi ipo ti o wa sile lai ka nnkan ti ofin fi le le gan gan lori enikeni ti o ba fi egbe sile lori oye paapajulo ni iru ipo ti ogbeni Saraki di mu. Ni ibi Ipade ti Oshimole ati awon loruko-loruko labe asia egbe APC ni pelu Aare Muhammadu Buhari lori...

Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc

Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Are Ile-igbimo Asofin Sile

Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Are Ile-igbimo Aosfin Sile Won ti fi awon idi ti Saraki fi gbodo fi ipo ti o wa sile lai ka nnkan ti ofin fi le le gan gan lori enikeni ti o ba fi egbe sile lori oye paapajulo ni iru ipo ti ogbeni Saraki di mu. Ni ibi Ipade ti Oshimole ati awon loruko...

Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc

Ki Bukola Saraki Tete Fi IPO Re Sile Ni Kiakia O – OSHIOMOLE

Alaga fun gbogbo egbe APC ni gbogbo orile ede Nigeria; iyen ogbeni Adams Oshiomole ti ke gbajari sita wipe ki Gomina ipinle Kwara teleri ti o je Are fun awon asofin-agba kuro lori oye ti o wa nitori awon idi ti o fi lele ninu iroyin yii. Ni ibi Ipade ti Oshimole ati awon loruko-loruko...

babangida-baba-elections-2019

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019 Ogagun teleri ti o ti dari orile ede Nigeria tele-tele ti f’owo si gbigbe igba ibo fun eni kan laarin awon egbe oselu ti o wa ni orile ede Nigeria; awon eniyan ko gbaagbo sugbon o wipe eni ti oun fe niyen. Gbogbo wa ni...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.