Category - Gists

Ayaba Alaafin Oyo, Olori Ola ko ile fun iya e

Ayaba Alaafin Oyo, Olori Ola ko ile fun iya e

Ayaba Alaafin Oyo, Olori Ola ko ile fun iya e Olori Ola Adeyemi, aya Alaafin Oyo ti o kere ju ti o je omo odun meta din l’ogbon ni odun ti o koja se ko ile fun iya e. E tun le ka: Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya O fi aworan ile naa si ori ero ayelujara (instagram)...

Idi ti Wuraola Ogunwusi ayaba Ooni ti ilu Ife se maa n wo aso funfun

Idi ti Wuraola Ogunwusi ayaba Ooni ti ilu Ife se maa n wo aso funfun

Idi ti Wuraola Ogunwusi ayaba Ooni ti ilu Ife se maa n wo aso funfun Olori Wuraola Ogunwusi, aya oba alayeluwa Ooni ti ilu Ife Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) teletele rii soro fun awon oniroyin nipa ise re ati igbesi aye re ninu aafin. Bawo ni e se iyipada lati igbesi aye eniyan...

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun Davido ti se afihan wipe oun ko ni ikun sinu kankan si enikeni ti o ro wipe oun ni owo ninu iku Tagbo. Osere ‘binrin Caroline Danjuma ti o fi esun kan wipe o ni owo ninu iku Tagbo ti o si rii pe o lo si ago olopa, Davido ti won ti tu...

Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re

Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re

Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re Laipe yii, gbaju-gbaja osere ‘kunrin, Odunlade Adekola so ninu ifi oro we oro kan nipa idi ti oun se pinu lati pada lati tesiwaju ninu eko re. Ibeere Akoko: Se looto ni e si je akeeko ni ile eko giga ti ipinle Eko? Odunlade: Yes I am...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.