Category - Lifestyle

ORISUN-TV-MERCY-AIGBE-#ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe

#ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe

#ASIRI: Awon Nnkan Ti E Ko Mo Nipa MERCY Aigbe Orisun l’agba gege bi a ti mo! Eyi lo mu ki a se agbekale “Mimo awon Gbajumo” lori Orisun fun awon eniyan ti ko mo won. Lori abala yii ni a ti yannanaa ohun ti awon eniyan le ma mo nipa Gbajumo osere nla nni MERCY AIGBE. E...

RUSSIA-2018-Victor-moses-fifa-world-cup

Iberu-Bojo Ni Awon Argentina Yoo Fi Bawa Gba Boolu – Victor Moses

Ibere-Bojo Ni Awon Argentina Yoo Fi Bawa Gba Boolu – Victor Moses Agbaboolu fun iko Chelsea ni oke-okun, ogbeni Victor Moses ti fiye wa wipe Orile ede Nigeria yoo ja awon Argentina laya nibi idije Group D ti won fiwon si fun FIFA world Cup RUSSIA 2018. Iko Super Eagles yoo koju awon...

Russia-2018-Obafemi-martins-nigerian-super-eagles

Awon Agbaboolu Nla Ti O Ye K’o Lo Gba RUSSIA 2018

Awon Agbaboolu Nla Ti O Ye K’o Lo Gba RUSSIA 2018 Bi o ti je wipe a ti gbe awon omo jade fun Boolu RUSSIA 2018, awon agbaboolu kookan si wa ti o ye ki won gbe jade fun idije naa. Awon meji ni a o yananaa loni. Nigeria n yangan wipe awon ni awon egbe agbaboolu ti o kere lojo ori...

Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so

Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so

Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so First Lady Mavin iyen Tiwa Savage soro nibi iforoworo kan pelu awon oniroyin nipa igbesi aye e ati awon nkakan ti awon eyan ko mo nipa e. E tun le ka: Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Gbaju-gbaja olorin naa ti won beere lowo e...

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Baba gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe se alaisi ni ale ana. Osere naa ti o gbe aworan abela si ori ero ayelujara so wipe baba oun ti ku ti o si n s’ofo baba re lowolowo. E tun le ka: Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 re Ti e ba...

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.