Tag: YORUBA

Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Watch Video
Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ

orisun

09/01/2019

235

Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ Ile ẹjọ nla High Court ni ipinlẹ eko ni oni ọjọ aje ti sun igbẹjọ ati gbigbe Arẹ ẹgbe awọn agbẹjọro ati adajọ ni ori

Watch Video
ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION Watch Video
#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

orisun

31/10/2018

710

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)? Lọsọọsẹ ni Abẹrẹ orin gẹgẹ bi awọn ololufẹ Atabatubu ṣe maa n pee maa n fi orin aladun da awọn ti o n wo amohunmaworan ileeṣẹ

Watch Video
ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION Watch Video
#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii

orisun

31/10/2018

1272

#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii Gẹgẹ bi ẹyin ololufẹ Atabatubu ti mọ olorin naa, amuludun ni; bẹẹni akọrin ni loju agbo. Pẹlu ijo, ọyaya ati orin ni o fi pari Eto Baba Eto lọsẹ y

Watch Video
IJEBUU-IJEBu-ACCIDENT IJEBUU-IJEBu-ACCIDENT Watch Video
E Wo Bi IJEBUU Se Bo Lowo Ijamba Ina Ni Ile-Itura Ti O Sun Si

orisun

14/06/2018

449

Bi IJEBU Se Bo Lowo Ijamba Ina Ni Ile-Itura Ti O Sun Si Ogbeni Omotayo Amokade ti gbogbo aye mo si Ijebuu fi fanran kan ranse si ori ero alatagba loni ojo ru lati fi dupe lowo olorun pe o yo ninu ewu ijamba ina ti o sele ni ile-itura ti o de si. Gege Watch Video

image Watch Video
Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Ona kakanfo Je Ni Ilu Oyo

orisun

31/05/2018

494

Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Onakakanfo Je Ni Ilu Oyo Ileese Telifisan Orisun wa nibi ayeye Ifijoye ti won se ni Ilu Oyo fun Are Onakakanfo tuntun ni awujo awon omo Yoruba ni Ilu Nigeria ati kaakakiri gbogbo agbaye ti awon omo Nigeria wa. Pelu Ijo ati ayo

Watch Video
Arsenal-europa-league-iwobi-wenger Arsenal-europa-league-iwobi-wenger Watch Video
A TI N GBARADI FUN EUROPA LEAGUE NITORI ARSENE WENGER – IWOBI

orisun

03/05/2018

408

Agbaboolu fun Orile ede Nigeria, iyen ALEX IWOBI ti so wipe awon egbe agbaboolu Arsenal ti n gbaradi fun ifesewonse EUROPA LEAGUE nitori Akonimoogba Arsene Wenger ti o fe fi egbe naa sile leyin idije naa. Ni ose ti o koja ni won koju egbe Atletico Madrid ninu

Watch Video
Gay-Antigay-uk-us-lesbians Gay-Antigay-uk-us-lesbians Watch Video
Prime Minista Orile Ede UK Ti So Wipe Ki Won Gbagbe Ofin T’Ode Awon GAY

orisun

17/04/2018

359

Prime Minista Orile Ede UK Ti So Wipe Ki Won Gbagbe Ofin T’Ode Awon GAY Prime Minista ti Orile ede United Kingdom iyen Theresa May ti fun Nigeria ati awon orile ede miran ti o wa ni abe Egbe Commonwealth ni amoran lati gba Igbeyawo Okunrin ati okunrin, b

Watch Video
Gbayi-kiss-daniel-cdq-music Gbayi-kiss-daniel-cdq-music Watch Video
CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI

TeeMirror

27/03/2018

1081

CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI Asiwaju agba fun Ileese NSNS ti awo orin ogbeni CDQ ti n jade ni o parapo pelu Kiss Daniel ti o sese di oga ara re naa lati gbe orin ‘Gbayi’ jade fun igbadun awon ololufe won. Gbogbo wa

Watch Video
Gas-Plant-GAASI-South-East-Petrol Gas-Plant-GAASI-South-East-Petrol Watch Video
Awon Gomina Ti Apa Ila-Oorun Si Iha Guusu Ti Gbimo Lati Se Oju Ona Ti Afefe GAS Yo Maa Gba

orisun

13/03/2018

321

Awon Gomina ti Ila-oorun si Iha Guusu ti bere ise lori sise Oju-ona fun Afefe GAS ti yio gba ipinle marun ti o wa ni ekun naa lati le jeki gbigbe Gaasi kakakiri le rorun, beeni ki o mu idagbasoke ba awon ipinle naa. Ninu atejade ti Alaga egbe awon Gomina naa i

Watch Video
lassa-fever-RATS-DISEASES-AFRICA lassa-fever-RATS-DISEASES-AFRICA Watch Video
Aarun Lassa Fever Ti Pa Dokita kan Ni Kogi, ati Awon Marun-un miiran Ni Ilu Ondo

orisun

24/01/2018

395

Dokita kan ti oruko re n je Idowu Ahmed ti o ko aarun lassa fever (iba-ekute) nigba ti o n se itoju omo osu meje kan, ni o ti gbemi mi bayii. Omo naa se alaisi ni ojo Eti, ojo ti won gbe wa si ile-iwosan fun itoju. A ri i gbo pe ile-iwosan kan Watch Video