Tag: OrisunTv

Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Watch Video
Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ

orisun

09/01/2019

234

Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ Ile ẹjọ nla High Court ni ipinlẹ eko ni oni ọjọ aje ti sun igbẹjọ ati gbigbe Arẹ ẹgbe awọn agbẹjọro ati adajọ ni ori

Watch Video
ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION Watch Video
#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

orisun

31/10/2018

710

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)? Lọsọọsẹ ni Abẹrẹ orin gẹgẹ bi awọn ololufẹ Atabatubu ṣe maa n pee maa n fi orin aladun da awọn ti o n wo amohunmaworan ileeṣẹ

Watch Video
orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi Watch Video
#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE

orisun

30/10/2018

1,237

#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE Lọse yii, awọn atọkun eto wa gbe awọn iroyin pataki wa si eti igbọ wa lori gbogbo ohun ti o n lọ ninu sinima ati awọn oṣere. Yatọ si iroyin, wọn sọrọ lori awọn sinima

Watch Video
Reno-Omokri-reno-omokri-orisun-buhari Reno-Omokri-reno-omokri-orisun-buhari Watch Video
Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se

orisun

13/06/2018

345

Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se Ni Ana ode oni, Oludari-agba fun egbe APC; iyen Ogbeni Bola Tinubu jade lati so wipe ise takun-takun ni Buhari ti gbe kale lati igba ti o ti bere ise. O wipe lododo, Buhari ti mu aw

Watch Video
bruce-melaye-ben-murrayMelaye-and-Murray-Bruce bruce-melaye-ben-murrayMelaye-and-Murray-Bruce Watch Video
Idi Ti Ben Bruce Fi Gbe Osuba Kare Fun DINO MELAYE Nitori Igbese Ti O Gbe Lo Si PDP

orisun

31/05/2018

340

Ben Bruce Ti Gbe Osuba Kare Fun DINO MELAYE Nitori Igbese Ti O Gbe Lo Si PDP Ogbeni Ben Bruce ti o ni ileese Silverbird ti gbe Osuba Kare fun MELAYE nitori wipe o fi egbe APC sile lo si PDP. Lana ode oni ni Dino melaye fi egbe APC sile ninu ipade awon igbimo

Watch Video
Messi-Nigeria v Argentina: Group F - 2014 FIFA World Cup Brazil Messi-Nigeria v Argentina: Group F - 2014 FIFA World Cup Brazil Watch Video
Ogbeni Lionel Messi So IDI Ti Iko Super Eagles Se Maa Le Fun Won Lati Koju

orisun

31/05/2018

415

Ogbeni Lionel Messi So IDI Ti Iko Super Eagles Se Maa Le Fun Won Lati Koju Olokiki agbaboolu Orile ede Argentina ti o je agba ninu awon agbaboolu ti egbe agbaboolu Barcelona ti gba wipe kikoju awon omo-iko super eagles yoo le fun awon beeni o si fi idi ti yoo

Watch Video
image Watch Video
Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

orisun

21/03/2018

602

Eku dede asiko yii eyin ololufe Orisun. Lori eto #Bosenlo t’oni ni a ti soro nipa ibasepo okunrin ati obirin ninu ile paapajulo eni ti o ye ki o se olori ile. Lara nnkan ti enikan so ni wipe O dara ki okunrin je olori nitori wipe lati inu itan wa ni a ti

Watch Video
Gas-Plant-GAASI-South-East-Petrol Gas-Plant-GAASI-South-East-Petrol Watch Video
Awon Gomina Ti Apa Ila-Oorun Si Iha Guusu Ti Gbimo Lati Se Oju Ona Ti Afefe GAS Yo Maa Gba

orisun

13/03/2018

321

Awon Gomina ti Ila-oorun si Iha Guusu ti bere ise lori sise Oju-ona fun Afefe GAS ti yio gba ipinle marun ti o wa ni ekun naa lati le jeki gbigbe Gaasi kakakiri le rorun, beeni ki o mu idagbasoke ba awon ipinle naa. Ninu atejade ti Alaga egbe awon Gomina naa i

Watch Video
Police-olopa-ekiti-death-orisun-tv Police-olopa-ekiti-death-orisun-tv Watch Video
E Wo Nnkan Ti Olopa Yii Se Ti O Fi Mu Emi Onimo Yi Lo Nilu Ekiti

orisun

13/12/2017

320

E Wo Nnkan Ti Olopa Yii Se Ti O Fi Mu Emi Onimo Yi Lo Nilu Ekiti Oga Olopa ni ilu Ekiti ti mu okan lara awon omo re; iyen CPL. Ayodele Famodimu ti won so wipe o yin ibon pa onimoto kan ni ojo isegun ti o koja. Agbenuso fun aeon Olopa, iyen SP Watch Video

image Watch Video
AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII

orisun

12/12/2017

463

AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se Watch Video