Tag: Obi

orisun-ojumo-ire-tv-ibo-obi-orisuntv orisun-ojumo-ire-tv-ibo-obi-orisuntv Watch Video
#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe)

orisun

31/10/2018

885

#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe) Gbogbo wa ti a ni obi, Yala awọn ni wọn bi wa ni tabi awọn ni wọn tọ wa dagba, Obi ni obi n jẹ. Awọn miran ni iya ti awọn miran si ni baba. Ni’bomiran,

Watch Video
image Watch Video
#OJURI: Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju?

orisun

12/12/2017

303

Nje Omode Leto Ati Gbe BABA Re Lo Si Ile EJO Nitori Aisi Itoju? Lori Eto Ojuri loni, Aralomo presenter bere lowo alejo re nipa awon nnkan ti awon omo le se lati fi ja fun eto won lati owo obi won. Bi awon omode se ni eto lati gba itoju gidi, aralomo bere nipa<

Watch Video
image Watch Video
E So Sinima Ti Omo Yin N Wo- Osere Hassan Goriola Si Awon Obi

orisun

03/08/2017

365

Osere sinima agbelewo, Ogbeni Hassan Goriola ti fi idi e mule peki awon obi maa so ohun ti awon omo won nwo lori amumaworan...

Watch Video
image Watch Video
Se O Leto Ki Obi Ko Omo Ni Eko Nipa Ibalopo?

orisun

03/08/2017

527

Se o leto ki n ko omo mi ni eko ibalopo gege bi Obi? Bawo ni mo se ma ko omo mi ni eko ibalopo? asiko wo loye kin ko omo mi ni eko ibalopo? se ko ni di eko odi ti mo ba ko omo mi nipa eko ibalopo?

Watch Video
image Watch Video
Igbese To Ye Ile Iwe Aladani Lori Ifipabanilopo

orisun

03/08/2017

490

Ile iwe Ijoba ati Ile iwe Aladani gbodo fi awon eto orisirisi sile lati fi dena de isele ifipabanilopo ni ile iwe won

Watch Video
image Watch Video
Tani Omo Le Fi Okan Tan Ti Ifipabanilopo Ba Waye

orisun

03/08/2017

352

Opo igba ni awon tio se janba ifipabanilopo ma n so wipe awon ko mo eni ti awon le fi okan tan ti iru nkan yi ba waye ati iha wo ni obi le ko si isele yi

Watch Video
image Watch Video
Awon Akiyesi Ti A O Fi Mo Boya Omo Ti Koju Ifipabanilopo

orisun

03/08/2017

373

Iroyin orisirisi lo nlo kaakiri ilu nipa bi awon agbalagba se n fi ipa ba awon omo kekeeke lopo, Awon akiyesi ti awon obi gbodo kiyesi ninu omo won...

Watch Video
Awon-omo-ile-iwe-psmb-children Awon-omo-ile-iwe-psmb-children Watch Video
Ni Ojoru Ikilo Jade Fun Awon Obi Lori Awon Omo Won Ni Ile-Iwe

orisun

21/07/2017

424

Ni ojo ojoru awon igbimo egbe Post Primary School Management Board

Watch Video