Tag: Nigeria

Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Paul-Usoro-NBA-NIGERIA-BAR-ASSOCIATION Watch Video
Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ

orisun

09/01/2019

235

Won Ti Sun Igbejọ Ọga Agba NBA; Ẹgbẹ Awọn Agbẹjọro Ati Adajọ Nigeria Si Iwaju Nitori Ẹsun Ikowojẹ Ile ẹjọ nla High Court ni ipinlẹ eko ni oni ọjọ aje ti sun igbẹjọ ati gbigbe Arẹ ẹgbe awọn agbẹjọro ati adajọ ni ori

Watch Video
orisun-ojumo-ire-tv-ibo-obi-orisuntv orisun-ojumo-ire-tv-ibo-obi-orisuntv Watch Video
#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe)

orisun

31/10/2018

885

#OjumoIRE: AWỌN NNKAN TI O YẸ KI ỌMỌ ṢE FUN AWỌN OBI (Gẹgẹ BI Ojuṣe) Gbogbo wa ti a ni obi, Yala awọn ni wọn bi wa ni tabi awọn ni wọn tọ wa dagba, Obi ni obi n jẹ. Awọn miran ni iya ti awọn miran si ni baba. Ni’bomiran,

Watch Video
Fayemi-signs-executive-order-for-free-education-in-Ekiti-orisun-tv-yoruba-ekiti Fayemi-signs-executive-order-for-free-education-in-Ekiti-orisun-tv-yoruba-ekiti Watch Video
#Orisun: FAYẸMI TI KEDE ILEEWE ỌFẸ NI IPINLẸ EKITI

orisun

24/10/2018

407

#Orisun: FAYẸMI TI KEDE ILEEWE ỌFẸ NI IPINLẸ EKITI Gomina ipinlẹ Ekiti ti polongo ẹkọ ọfẹ ni ipinlẹ ekiti loni ọjọru paapa julọ ni awọn ileewe ti ijọba ṣẹda rẹ ni ipinlẹ naa. Agbekalẹ owo fun igbedide eto ẹkọ bẹr

Watch Video
workers-minimum-wage-orisun-tv workers-minimum-wage-orisun-tv Watch Video
#Orisun: Ijọba Nigeria Le Fun Oṣiṣẹ Kọọkan Ni 30 Thousand Loṣu – Shehu Sanni

orisun

23/10/2018

484

#Orisun: Ijọba Nigeria Le Fun Oṣiṣẹ Kọọkan Ni 30 Thousand Loṣu – Shehu Sanni Sinetọ kan ni orilẹ ede Nigeria ti sọ wipe ko yẹ ki ijọba Nigeria maa palantia lori iye owo ti ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ n sọ wipe ki o jẹ oṣuw

Watch Video
Aisha-Buhari-orisun-tv-orisuntv Aisha-Buhari-orisun-tv-orisuntv Watch Video
Eyin Obinrin E Jade Lati Se Iselu O, Ki Awon Okunrin Ma Ro Yin Seyin – AISHA BUHARI

orisun

30/08/2018

392

Eyin Obinrin E Jade Lati Se Iselu O, Ki Awon Okunrin Ma Ro Yin Seyin – AISHA BUHARI Aya Aare orile ede yii, Eni-owo Aisha Buhari ti so ni ojoru osu kejo ti a wa yii pelu ipe fun awon obinrin lati dije fun awon ipo pataki ni orile ede Nigeria lati fi gbe

Watch Video
Saraki-sneaks-into-National-Assembly-leads-defection Saraki-sneaks-into-National-Assembly-leads-defection Watch Video
Ipababo Abija Ni Saraki Fi PDP Se O Bi A Se Gbo Wipe O Ti Di Adari Agba Fun Egbe-Oselu PDP

orisun

03/08/2018

421

Ipababo Abija Ni Saraki Fi PDP Se O Bi A Se Gbo Wipe O Ti Di Alaga Agba Fun Egbe-Oselu PDP Gegebi a ti rii gba lowuro yii, Leyin ipade laarin awon egbe-oselu PDP, Aare fun gbogbo omo ile-igbimo Asofin, Bukola Saraki ni a gbo wipe o won ti yan-an gege bi adari

Watch Video
Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Watch Video
Ki Bukola Saraki Tete Fi IPO Re Sile Ni Kiakia O – OSHIOMOLE

orisun

02/08/2018

432

Alaga fun gbogbo egbe APC ni gbogbo orile ede Nigeria; iyen ogbeni Adams Oshiomole ti ke gbajari sita wipe ki Gomina ipinle Kwara teleri ti o je Are fun awon asofin-agba kuro lori oye ti o wa nitori awon idi ti o fi lele ninu iroyin yii. Ni ibi Ipade ti Oshimo

Watch Video
babangida-baba-elections-2019 babangida-baba-elections-2019 Watch Video
E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019

orisun

18/07/2018

398

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019 Ogagun teleri ti o ti dari orile ede Nigeria tele-tele ti f’owo si gbigbe igba ibo fun eni kan laarin awon egbe oselu ti o wa ni orile ede Nigeria; awon eniyan ko gbaagbo sugbon o wipe eni t

Watch Video
Fayose-ekiti-pdp-elections-2019 Fayose-ekiti-pdp-elections-2019 Watch Video
E Wo Atejade Egbe PDP Ti O Fihan Wipe Won N Gbimo Lati Fi Ipa Gba Gbogbo Ilu Ekiti

orisun

13/07/2018

401

E Wo Atejade Egbe PDP Ti O Fihan Wipe Won N Gbimo Lati Fi Ipa Gba Gbogbo Ilu Ekiti Egbe Oselu (PDP) ti ilu Ekiti ti n f’arasise lati je ki a mo wipe awon yoo fi ipa gba ijoba lowo egbe APC gege bi atejade ti a ri gba. Eyi jade ni ana ode Watch Video

Buhari-nigezie-tv-orisun-tv-xtreme Buhari-nigezie-tv-orisun-tv-xtreme Watch Video
Lodun T’O N Bo, Egbe PDP Ni Yoo Wa Ni Ipo Aare Lati Dari Ayeye Iranti Ojo Ti IJOBA-Awa’rawa (Democracy Day)

orisun

30/05/2018

385

Lodun T’O N Bo, Egbe PDP Ni Yoo Wa Ni Ipo Aare Lati Dari Ayeye Iranti Ojo Ti IJOBA-Awa’rawa (Democracy Day) Alaga egbe Oselu PDP; iyen Peoples Democratic Party (PDP) Prince Uche Secondus ti so wipe Aare Muhammadu Buhari ti se Ayeye Ominira Ijoba-aw

Watch Video