Tag: music

adekunle-gold-and-pheelz adekunle-gold-and-pheelz Watch Video
#OrinTitun: ADEKUNLE GOLD (@adekunleGold) Ft. PHEELZ – IRE (remix)

orisun

10/01/2019

189

ADEKUNLE GOLD Ft. PHEELZ – IRE (remix) Lẹyin ti orin “IRE” ti lọ kaakakiri agbanla aye, Adekunle Gold ati ọrẹ rẹ ti o jẹ ẹni ti o maa n po gbogbo eroja orin mọ ara wọn ti wọn yoo fi da ẹyọkan; iyẹn PHEELZ gbe remix o

Watch Video
teni-entertainer-uyo-meyo-yellow teni-entertainer-uyo-meyo-yellow Watch Video
#OrinTitun: TENI (@tenientertainer) – UYO MEYO

TeeMirror

10/01/2019

146

TENI – UYO MEYO Tẹni ni Olorin ti aye n fẹ ni asiko yii; oun ni ọmọ ti wọn sọ lọwọ-lọwọ. O ti gbe fidio miran jade bayii pẹlu awọn aworan lati igba ti o ti bẹrẹ orin kikọ titi o fi di ilumọọka. Uyo Meyo jẹ orin ti aw

Watch Video
Shina-peters-shina-music-birthday-60years-60-old Shina-peters-shina-music-birthday-60years-60-old Watch Video
E Wo Awon Aworan Yii Ti Sir SHINA PETERS Fi Se Ojo Ibi Omo-odun Ogota

orisun

31/05/2018

317

E Wo Awon Aworan Yii Ti Sir SHINA PETERS Fi Se Ojo Ibi Omo-odun Ogota Olorin Gbajumo Nla ti awon eniyan mo si Sir SHINA PETERS ti aye n pe ni Oludasile Afro-Juju music ni gbogbo aye n pe omo odun ogota loni..Inu wa si dun lati baa se ojo ibi naa. Loni ogbon oj

Watch Video
Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so Watch Video
Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so

TeeMirror

31/10/2017

398

Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so First Lady Mavin iyen Tiwa Savage soro nibi iforoworo kan pelu awon oniroyin nipa igbesi aye e ati awon nkakan ti awon eyan ko mo nipa e. E tun le ka: Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Gbaju-gbaja

Watch Video
Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Watch Video
Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 e

TeeMirror

30/10/2017

339

Osere ‘binrin, Biodun Okeowo s’oro leyin ti eyan kan ji iPhone 7 e Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gege bi osere naa se so, ero

Watch Video
Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Watch Video
Toyosi Gba Awon Obirin Ni Amoran Lori Awon Okunrin

TeeMirror

30/10/2017

502

Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s’oro Irawo tele-tele ti ere sinima agbelewo Jenifa’s Diary, Juliana Olayode ti gbogbo eniyan mo si Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won sele baa won okunrin soro ati iru esi t

Watch Video
Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin Watch Video
Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin

TeeMirror

19/10/2017

415

Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin In an emotional post, Tonto Dikeh revealed what life was like for her as a newbie in Lagos 10 years ago and how she betrayed a helper and close friend because of her ex-husband, Churchill. E tun le ka:

Watch Video
Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun Watch Video
Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

TeeMirror

17/10/2017

433

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun Davido ti se afihan wipe oun ko ni ikun sinu kankan si enikeni ti o ro wipe oun ni owo ninu iku Tagbo. Osere ‘binrin Caroline Danjuma ti o fi esun kan wipe o ni owo ninu iku Tagbo ti o si Watch Video

malaika-ORISUN malaika-ORISUN Watch Video
Olorin Fuji Alao Malaika Ra Ile Nla Si Lekki

orisun

06/10/2017

423

Ilumooka olorin fuji, Alhaji Sulaimon Alao Adekunle Malaika ti pari ile nla tuntun ti o n ko si Lekki Phase One, Lagos. Gegebi iroyin ti o n kan kakaakiri, Malaika n palemo lati se ayeye isile ni December odun yii.. Olorin Maolaika so eleyi di mimo ni ibi ayey

Watch Video
image Watch Video
AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON

orisun

05/10/2017

529

AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON OLORIN JAYWON ti aye mo ko awon orin bii This Year, Facebook Love, Joromi Jomi, Banuso ati beebeelo ni alejo wa lori Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo… O dahun ibeere ti o nii se pelu bi o se n ri im

Watch Video