Tag: movies

orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi Watch Video
#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE

orisun

30/10/2018

1,237

#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE Lọse yii, awọn atọkun eto wa gbe awọn iroyin pataki wa si eti igbọ wa lori gbogbo ohun ti o n lọ ninu sinima ati awọn oṣere. Yatọ si iroyin, wọn sọrọ lori awọn sinima

Watch Video
Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Watch Video
Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun

TeeMirror

30/10/2017

338

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Baba gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe se alaisi ni ale ana. Osere naa ti o gbe aworan abela si ori ero ayelujara so wipe baba oun ti ku ti o si n s’ofo baba re lowolowo. E tun le ka: Biodun Okeowo s’oro

Watch Video
Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Watch Video
Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 e

TeeMirror

30/10/2017

339

Osere ‘binrin, Biodun Okeowo s’oro leyin ti eyan kan ji iPhone 7 e Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gege bi osere naa se so, ero

Watch Video
Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Watch Video
Toyosi Gba Awon Obirin Ni Amoran Lori Awon Okunrin

TeeMirror

30/10/2017

502

Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s’oro Irawo tele-tele ti ere sinima agbelewo Jenifa’s Diary, Juliana Olayode ti gbogbo eniyan mo si Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won sele baa won okunrin soro ati iru esi t

Watch Video
Igba meje ti Mercy Aigbe ati Omo re gbe ara oge titun yo Igba meje ti Mercy Aigbe ati Omo re gbe ara oge titun yo Watch Video
Igba meje ti Mercy Aigbe ati Omo re gbe ara oge titun yo

TeeMirror

25/10/2017

455

Igba meje ti Mercy Aigbe ati Omo re gbe ara oge titun yo Gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe ti o ti ni wahala ni ile oko re ati fun bi ose die seyin ti o si ti pinu lati fi oju fo gbogbo rogbo diyan naa, ki o si maa dunu. E tun le ka: Watch Video

Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re fi jo ara won Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re fi jo ara won Watch Video
Nkan Ti Mercy Aigbe Ati Omo Re Michelle Fi Jo Ara Won

TeeMirror

25/10/2017

442

Nkan ti Mercy Aigbe ati omo re Michelle fi jo ara won Olorun fi arewa odo’mobinrin omo odun merin din logun Michelle Gentry ta Mercy Aigbe lo re. Arewa odo’mobinrin alawo dudu naa fi ewa re han o si tun feran lati maa se bii ibeji iya re ni gbogbo igba. Ib

Watch Video
Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin Watch Video
Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin

TeeMirror

19/10/2017

415

Atejise ti Tonto Dike ko si ore re ti o da nitori okunrin In an emotional post, Tonto Dikeh revealed what life was like for her as a newbie in Lagos 10 years ago and how she betrayed a helper and close friend because of her ex-husband, Churchill. E tun le ka:

Watch Video
Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re Watch Video
Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re

TeeMirror

09/10/2017

504

Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re Laipe yii, gbaju-gbaja osere ‘kunrin, Odunlade Adekola so ninu ifi oro we oro kan nipa idi ti oun se pinu lati pada lati tesiwaju ninu eko re. Ibeere Akoko: Se looto ni e si je akeeko ni ile eko giga ti ipinle

Watch Video
antar-laniyan-orisun antar-laniyan-orisun Watch Video
Araosan Lo Ba Mi De Nu Ko Iyawo Mi- Antar Laniyan

orisun

04/10/2017

449

Ninu industry ere Yoruba, Antar Laniyan je oruko nla ti gbogbo eeyan fe diro mo. Antar Laniyan je ogbontarigi osere ti gbogbo awon adari ere si n fe ki o ma wa ninu ere won ni gbogbo igba nitori bi ose ma n se daadaa ninu ipa ti won ba fun. Looto, Ipinle osun

Watch Video
nollywood-orisun nollywood-orisun Watch Video
Awon Osere Yoruba Ti Won Fera Won, NUMBER 1 MA YA YIN LENU

orisun

26/09/2017

734

Awon osere er agbelewo Yoruba ti won fe arawon nisu loka po gan ni nollywood ti awon fans won o de mo nipa e ti won si n fi igbe aye won si abele….   Damola Olatunji and Bukola Awoyemi Ilumooka osere, damola olatunji se igbeyawo pelu bukola awoyemi ti o

Watch Video