Tag: Iroyin

Simi-and-Adekunle-Gold-engaged-hold-wedding-introduction-nigezie-xtreme Simi-and-Adekunle-Gold-engaged-hold-wedding-introduction-nigezie-xtreme Watch Video
Iroyin Ti JADE Wipe ADEKUNLE GOLD Ati Simi Ṣe Eto MọmiNmọọ

orisun

18/12/2018

333

Iroyin Ti JADE Wipe ADEKUNLE GOLD Ati Simi Ṣe Eto MọmiNmọọ Gẹgẹ bi a ti rii gbọ, Adekunle Gold ati olohun ṣuga ti gbe ibaṣepọ wọn de ibi giga ti wọn si ṣe eto mọminmọọ ni opin ọsẹ ti o kọja yii. Gẹgẹ bi Ileeṣẹ iroy

Watch Video
orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi orisun-tv-feyikemi-toyin-oki-olayemi Watch Video
#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE

orisun

30/10/2018

1,237

#MilikiEXPRESS: AWỌN IROYIN LORI AWỌN SINIMA ATI AWỌN OṢERE Lọse yii, awọn atọkun eto wa gbe awọn iroyin pataki wa si eti igbọ wa lori gbogbo ohun ti o n lọ ninu sinima ati awọn oṣere. Yatọ si iroyin, wọn sọrọ lori awọn sinima

Watch Video
Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Watch Video
Ki Bukola Saraki Tete Fi IPO Re Sile Ni Kiakia O – OSHIOMOLE

orisun

02/08/2018

431

Alaga fun gbogbo egbe APC ni gbogbo orile ede Nigeria; iyen ogbeni Adams Oshiomole ti ke gbajari sita wipe ki Gomina ipinle Kwara teleri ti o je Are fun awon asofin-agba kuro lori oye ti o wa nitori awon idi ti o fi lele ninu iroyin yii. Ni ibi Ipade ti Oshimo

Watch Video
Reno-Omokri-reno-omokri-orisun-buhari Reno-Omokri-reno-omokri-orisun-buhari Watch Video
Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se

orisun

13/06/2018

345

Ogbeni Reno Omokri So Wipe Iro Ni Tinubu N Pa Nipa Pe BUHARI Ti Mu Ileri Re Se Ni Ana ode oni, Oludari-agba fun egbe APC; iyen Ogbeni Bola Tinubu jade lati so wipe ise takun-takun ni Buhari ti gbe kale lati igba ti o ti bere ise. O wipe lododo, Buhari ti mu aw

Watch Video
image Watch Video
Bi Fayemi Se Ja Ilu EKiti lole – IGBIMO IWADI

orisun

14/12/2017

327

Bi Fayemi Se Ja Ilu EKiti lole – IGBIMO IWADI Iroyin ti o n de si eti igbo wa losan oni ni wipe Ajo Idajo Ati Iwadi ti ilu ekiti gbe kale lati seto lori inadura labe ijoba Kayode Fayemi ti o je gomina teleri ti pariwo sita wipe, Gomina teleri naa gbodo s

Watch Video
image Watch Video
Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

orisun

12/12/2017

314

Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O Adari Ere ati ogbountarigi elere so wipe Oko Mercy Aigbe n tahun si oun lori ero ayelujara wipe ki oun fi Mercy sile. Iyalenu ni o je fun wa bi Lege miami se so wipe oun ko ni nnkankan pelu Oser

Watch Video
Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so Watch Video
Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so

TeeMirror

31/10/2017

398

Tiwa Savage soro nipa bi oun se feran lati maa so First Lady Mavin iyen Tiwa Savage soro nibi iforoworo kan pelu awon oniroyin nipa igbesi aye e ati awon nkakan ti awon eyan ko mo nipa e. E tun le ka: Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Gbaju-gbaja

Watch Video
Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Watch Video
Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun

TeeMirror

30/10/2017

338

Baba osere ‘binrin Mercy Aigbe je ipe olorun Baba gbaju-gbaja osere ‘binrin Mercy Aigbe se alaisi ni ale ana. Osere naa ti o gbe aworan abela si ori ero ayelujara so wipe baba oun ti ku ti o si n s’ofo baba re lowolowo. E tun le ka: Biodun Okeowo s’oro

Watch Video
Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Watch Video
Biodun Okeowo s’oro leyin ti won ji iPhone 7 e

TeeMirror

30/10/2017

339

Osere ‘binrin, Biodun Okeowo s’oro leyin ti eyan kan ji iPhone 7 e Gbaju-gbaja osere ‘birin Biodun Okeowo ti se ileri lati san esan gidi fun enikeni ti o ba ni alaye nipa ero ibanisoro iPhone 7 e ti o ni wura lara ti won ji. Gege bi osere naa se so, ero

Watch Video
Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s'oro Watch Video
Toyosi Gba Awon Obirin Ni Amoran Lori Awon Okunrin

TeeMirror

30/10/2017

502

Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won se le ba okunrin s’oro Irawo tele-tele ti ere sinima agbelewo Jenifa’s Diary, Juliana Olayode ti gbogbo eniyan mo si Toyo Baby gba awon obirin ni amoran lori bi won sele baa won okunrin soro ati iru esi t

Watch Video