Skip to content

Ijoba Apapo Kede Ojo Aje Ni Ojo Isinmi Igbominira Nigeria

Ijoba apapo tip e ojo aje, Monday October 2nd, ni ojo isinmi lati fi se ajoyo ojo igbominira orileede Nigeria. Lt Gen Abdulrahman Dambazau (retd.) ti o je minisita fun interior lo so ikede yi di mimo ni ojo ojoru September 27,ni Abuja , nibiti o ti ke pea won omo Nigeria lati fi owosowopo lati gbe orileede laruge, ki won si fi imosokan. Ninu iwe ti permanent secretary si ministita, Abubakar Magaji, ko jad, o so wipe ijoba apapo si n tiraka lati jeki orileede Nigeria wan i isokan.

E TUN LE KA; Ijoba Ipinle Eko Kede No Movement Ni Ale Ni Ikorodu

“Government’s commitment to promoting national unity, economic growth and political development on democratic principles. In the past 57 years, Nigeria had made much progress and positive impact not only on its citizens but also on human development globally.The minister enjoined all Nigerians to remain steadfast in the love and care of the country, noting that a strong sense of ownership of one’s country is vital to the sustainable development of any nation.”

TABI KE KA: Ijoba Eko Setan Lati Palemo Abe Bridge Ojuelegba ati Ikeja

Minista ki gbogbo omo Nigeria ni ile ati ni oke okun fun aduroti ati atilehin ti won fun Aare Muhammmad Buhari… O si ki gbogbo omo Nigeria Ku Ayeye Ominira