Tag: eto baba Eto

ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION Watch Video
#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii

orisun

31/10/2018

1272

#EtoBabaETO: Atabatubu Fi Orin Ati Ijo Da Awon Eniyan Lara Ya Lori Eto Baba Eto Osẹ Yii Gẹgẹ bi ẹyin ololufẹ Atabatubu ti mọ olorin naa, amuludun ni; bẹẹni akọrin ni loju agbo. Pẹlu ijo, ọyaya ati orin ni o fi pari Eto Baba Eto lọsẹ y

Watch Video
image Watch Video
Kola Ogunkoya Ko SWEETY BABY Pelu Atabatubu

orisun

04/10/2017

352

  Olorin Kola Ogunkoya ti o ko orin gbajumo “Sweety Baby” ni bi 90’s wa si ori eto baba eto pelu atokun wa Atabatubu. Lori eto naa, Ogbeni Kola Ogunkoya ko orin naa lati fi da wa lara ya lori eto naa pelu Atabatubu lori eto (Live).. E wo

Watch Video
image Watch Video
AWON OMO AIYE ISIN O FIBE FERAN GOSPEL MUSIC-KUNLE TRINITY

orisun

25/08/2017

419

Kunle Trinity ti o je olorin emi ni alejo wa lori eto baba eto pelu Atabatubu ni ibi ti won ti soro nipa orin emi (Gospel Music)

Watch Video
image Watch Video
E Gbo Orin Ti Kunle-Trinity Ko Pelu Atabatubu

orisun

24/08/2017

339

Lori eto wa Eto Baba Eto ti Atabatubu je olootu re, Kunle-Trinity fi orin dara. Kunle-Trinity fi orin yin olorun logo ni ona ara.

Watch Video
image Watch Video
Ewon Egbere Ni Fun Ara ati Ore Eni To N Se Piracy-NFVCB

orisun

11/08/2017

363

Piracy je nkan ti o n ba inu awon ti o wa ni Entertainment Industry je latari pe awon eni ibi won yi o je ki won jere ise owo won. Oga agba Ajo NFVCB ti o je alejo wa lori Eto baba Eto

Watch Video
image Watch Video
Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

orisun

09/08/2017

428

FVCB je ajo ti o wa ni idi ki won ma ri wipe gbogbo orin ati sinima agbelewo pe oju osunwon fun awon agbalagba ati omode ti won ma wo.

Watch Video
image Watch Video
Se Gbogbo Nkan To N Sele Ninu Ile Wa Lori Ero Ayelujara

orisun

04/08/2017

363

Ni opo igba ni a ma n ri fideo tabi aworan nipa bi igbe aiye awon eyan se n lo lori ero ayelujara. opo igba ni awon eniyan ma n fi gbogbo nkan ti o n sele ninu ile ati igbeyawo won sori ero ayelujara ti o si ti fa ede aiyede laarin ebi ati ara

Watch Video
image Watch Video
Idi Ti Ijoba Se Da Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB)

orisun

03/08/2017

353

Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB) lo wa ni idi ki won ri daju wipe gbogbo nkan ti o wa ni ori amumaworan ba ilana ijoba wa mu

Watch Video
efcc dufafa efcc dufafa Watch Video
Ajo EFCC Lo Fi Ipa Je Ki N Tu Asiri Jonathan O

orisun

24/01/2017

246

Ajo EFCC Lo Fi Ipa Je Ki N Tu Asiri Jonathan O. Oro yii lo jade lati enu agbenuso ati ami kan fun Aare Orile ede wa teleri, Ogbeni Goodluck Jonathan ti won si lo awon iwe eri ayederu lati fi je ki n tu Asiri naa.

Watch Video
mauritius mauritius Watch Video
Se O ye Ki Ipo Aare Je Oye Idile Ni Ile Africa Tabi Nigeria

orisun

23/01/2017

479

Se O ye Ki Ipo Aare Je Oye Idile Ni Ile Africa Tabi Nigeria ni ibeere ti a n bere lowo awon eniyan bi o se je wipe ni ilu mauritius ni iroyin ti gbe wipe Anerood ti fe gbe oye fun omo re.

Watch Video