Tag: Atabatubu

OBAT-OBATAYO-ORISUN-ATABATUBU OBAT-OBATAYO-ORISUN-ATABATUBU Watch Video
#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ MỌ AMI ORI ỌRỌ YII? “Abetilukara Bi Ajere” – OBAT

orisun

31/10/2018

700

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ MỌ AMI ORI ỌRỌ YII? “Abetilukara Bi Ajere” – OBAT Lori eto t’oni, Atabatubu bi alejo rẹ ni abala ami-ori-ọrọ nipa ami ori ọrọ kan ti awọn eniyan maa n fi n ki ọlọrun. Alejo rẹ OBATAYO ti gb

Watch Video
ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION Watch Video
#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

orisun

31/10/2018

711

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)? Lọsọọsẹ ni Abẹrẹ orin gẹgẹ bi awọn ololufẹ Atabatubu ṣe maa n pee maa n fi orin aladun da awọn ti o n wo amohunmaworan ileeṣẹ

Watch Video
image Watch Video
Kola Ogunkoya Ko SWEETY BABY Pelu Atabatubu

orisun

04/10/2017

352

  Olorin Kola Ogunkoya ti o ko orin gbajumo “Sweety Baby” ni bi 90’s wa si ori eto baba eto pelu atokun wa Atabatubu. Lori eto naa, Ogbeni Kola Ogunkoya ko orin naa lati fi da wa lara ya lori eto naa pelu Atabatubu lori eto (Live).. E wo

Watch Video
image Watch Video
Se O Ye Ki Osere Tabi Akorin Gbe Igba Idibo?

orisun

08/09/2017

301

Opo osere ati awon ti won n ko orin ni won ti gbe igba ibo seyin ri. Awon bi 9ice, Funke Adeshiyan, Desmond Elliot atibeebeelo. Awon kan gbe igba ibo won si yege ti awon kan o si yege. Sugbon se o ye ki awon osere tabi olorin wa yi ki won maa gbe igba

Watch Video
image Watch Video
EWO BI ATABATUBU ATI OLORI SE N LU GANGAN

orisun

29/08/2017

437

Atabatubu ati Olori kemi ti tun de gegebi ise won lati ma mu yin larada lori eto Ojumo ire. Loteyi, atabatubu ati olori kemi di onilu ti won si korin si.

Watch Video
image Watch Video
Nje O Dara Ki Eniyan Fi ISE Ijoba Sile Se ISE ORIN?

orisun

25/08/2017

358

lORI ETO OJUMO IRE PELU ATABATUBU ATI OLORI KEMI, WON GBE AKOLE PE SE O DARA KI ENIYAN FI ISE IJOBA SILE LATI SISE ORIN

Watch Video
image Watch Video
AWON OMO AIYE ISIN O FIBE FERAN GOSPEL MUSIC-KUNLE TRINITY

orisun

25/08/2017

420

Kunle Trinity ti o je olorin emi ni alejo wa lori eto baba eto pelu Atabatubu ni ibi ti won ti soro nipa orin emi (Gospel Music)

Watch Video
image Watch Video
E Gbo Orin Ti Kunle-Trinity Ko Pelu Atabatubu

orisun

24/08/2017

340

Lori eto wa Eto Baba Eto ti Atabatubu je olootu re, Kunle-Trinity fi orin dara. Kunle-Trinity fi orin yin olorun logo ni ona ara.

Watch Video
image Watch Video
Bi Trinity Se Waye Ninu Oruko KUNLE-TRINITY

orisun

24/08/2017

335

Lori eto wa Eto baba eto loni, Alejo wa Kunle Trinity pelu Atabatubu soro nipa nnkan ti o bi Oruko ti o n je.  O bere pelu bi o se n je Metalokan ati bi awon elegbe re ni kekere se maa n pe ni metalokan, nitori bi o se maa n yi orin kan si ona meta nipase

Watch Video
image Watch Video
Se Gbogbo Nkan To N Sele Ninu Ile Wa Lori Ero Ayelujara

orisun

04/08/2017

363

Ni opo igba ni a ma n ri fideo tabi aworan nipa bi igbe aiye awon eyan se n lo lori ero ayelujara. opo igba ni awon eniyan ma n fi gbogbo nkan ti o n sele ninu ile ati igbeyawo won sori ero ayelujara ti o si ti fa ede aiyede laarin ebi ati ara

Watch Video