Aregbesola Pe August 21 Ni Isese Day

isese-day-osun-osogbo-orisun
Description

Ijoba Ipinle Osun ti pe ojo aje, august 21, 2017 ni public holiday lati se ajoyo Ojo Isese ti won ma n se ni odoodun. Isese day je ojo ti won ma n gba isinmi fun awon elesin isembaye lati se ajoyo esin na lati owo ijoba rauf aregbesola.

E TUN LE KA: Bi Won Se Se Ayeye Odun Eegun Ni Ilu Ode Remo

Isese Day  gba gbogbo esin abalaye lati fi orisirisi esin won han ni ojo yi. Ijoba aregbesola ro awon ti o n se ajoyo yi pe ki won se ni ayo ati alafia lai fa ija tabi wahala ninu ipinle naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *