Hot news

All Videos : 519  Video Posted

Fayemi-signs-executive-order-for-free-education-in-Ekiti-orisun-tv-yoruba-ekiti Fayemi-signs-executive-order-for-free-education-in-Ekiti-orisun-tv-yoruba-ekiti Watch Video
#Orisun: FAYẸMI TI KEDE ILEEWE ỌFẸ NI IPINLẸ EKITI

orisun

24/10/2018

163

#Orisun: FAYẸMI TI KEDE ILEEWE ỌFẸ NI IPINLẸ EKITI Gomina ipinlẹ Ekiti ti polongo ẹkọ ọfẹ ni ipinlẹ ekiti loni ọjọru paapa julọ ni awọn ileewe ti ijọba ṣẹda rẹ ni ipinlẹ naa. Agbekalẹ owo fun igbedide eto ẹkọ bẹr

Watch Video
workers-minimum-wage-orisun-tv workers-minimum-wage-orisun-tv Watch Video
1
#Orisun: Ijọba Nigeria Le Fun Oṣiṣẹ Kọọkan Ni 30 Thousand Loṣu – Shehu Sanni

orisun

23/10/2018

149

#Orisun: Ijọba Nigeria Le Fun Oṣiṣẹ Kọọkan Ni 30 Thousand Loṣu – Shehu Sanni Sinetọ kan ni orilẹ ede Nigeria ti sọ wipe ko yẹ ki ijọba Nigeria maa palantia lori iye owo ti ẹgbẹ awọn oṣiṣẹ n sọ wipe ki o jẹ oṣuw

Watch Video
Buhari-oyetola-rauf-aregbesola-osun-state Buhari-oyetola-rauf-aregbesola-osun-state Watch Video
3
Buhari Gbe Osuba-Kare Fun Gomina Ti O Wo’le Ni Ipinle Osun

orisun

28/09/2018

202

Aarẹ Muhammadu Buhari ti ki ọgbẹni Isiaka Oyetọla ku oriire lẹyin ti o ti gbe’gba-oroke nibi eto idibo ti o kọja lọ ni ipinlẹ ọsun. Aarẹ Buhari ti fi ikini ranṣẹ si agọ awọn ẹgbẹ Oṣelu APC (All progressive Congress) bẹ

Watch Video
oselu-iselu-parties-2019-president-presidential oselu-iselu-parties-2019-president-presidential Watch Video
3
Eyi Ni Iye Awọn Eniyan Ti Wọn Ti Gba Fọọmu Fun Idije Ibo Aarẹ Orile Ede Nigeria Ni 2019

orisun

14/09/2018

161

Eyi Ni Iye Awọn Eniyan Ti Wọn Ti Gba Fọọmu Fun Idije Ibo Aarẹ Orile Ede Nigeria Ni 2019 Pẹlu gbogbo ohun ti o n ṣẹlẹ lori Ibo ti o n bọ ni ọdun 2019, Awọn Oloṣelu ti n gb’aradi pẹlu awọn igbesẹ t’oyatọ lati jẹ ki

Watch Video
Saraki-jonathan-bukola-goodluck Saraki-jonathan-bukola-goodluck Watch Video
2
Idi Ti Goodluck Jonathan Fi So Wipe Ti Ko Ba Si Ti Saraki, Ile-Asofin Yoo Ti Daru

orisun

30/08/2018

126

Idi Ti Goodluck Jonathan Fi So Wipe Ti Ko Ba Si Ti Saraki, Ile-Asofin Yoo Ti Daru Aare Orile ede Nigeria tele ri; Ogbeni Goodluck Ebele Jonathan ni ojoru ti o koja (August 29th) ni o gbe osuba-kare fun Aare Ile igbimo-asofin agba iyen Dokita Bukola Saraki fun

Watch Video
gabriel-jesus-manchester-city-ethad-stadium gabriel-jesus-manchester-city-ethad-stadium Watch Video
3
Idi Ti Ogbeni Gabriel Jesus Fi T’owo Bo’we Lati Duro Si MAN CITY Fun Odun Miran Sii

orisun

03/08/2018

127

Idi Ti Ogbeni Gabriel Jesus Fi T’owo Bo’we Lati Duro Si MAN CITY Fun Odun Miran Sii Agbaboolu fun iko-agbaboolu Manchester City pelu oruko Gabriel Jesus ti gba lati duro pelu awon akegbee re ni Man City fun b i odun die sii (2023). Jesus je omo odu

Watch Video
Saraki-sneaks-into-National-Assembly-leads-defection Saraki-sneaks-into-National-Assembly-leads-defection Watch Video
5
Ipababo Abija Ni Saraki Fi PDP Se O Bi A Se Gbo Wipe O Ti Di Adari Agba Fun Egbe-Oselu PDP

orisun

03/08/2018

185

Ipababo Abija Ni Saraki Fi PDP Se O Bi A Se Gbo Wipe O Ti Di Alaga Agba Fun Egbe-Oselu PDP Gegebi a ti rii gba lowuro yii, Leyin ipade laarin awon egbe-oselu PDP, Aare fun gbogbo omo ile-igbimo Asofin, Bukola Saraki ni a gbo wipe o won ti yan-an gege bi adari

Watch Video
Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Watch Video
3
Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Aare Ile-igbimo Asofin Sile

orisun

02/08/2018

156

Won ti fi awon idi ti Saraki fi gbodo fi ipo ti o wa sile lai ka nnkan ti ofin fi le le gan gan lori enikeni ti o ba fi egbe sile lori oye paapajulo ni iru ipo ti ogbeni Saraki di mu. Ni ibi Ipade ti Oshimole ati awon loruko-loruko labe asia egbe Watch Video

Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Watch Video
3
Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Are Ile-igbimo Asofin Sile

orisun

02/08/2018

120

Awon Idi Ti Saraki Fi Gbodo Fi IPO Are Ile-igbimo Aosfin Sile Won ti fi awon idi ti Saraki fi gbodo fi ipo ti o wa sile lai ka nnkan ti ofin fi le le gan gan lori enikeni ti o ba fi egbe sile lori oye paapajulo ni iru ipo ti ogbeni Saraki di Watch Video

Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Saraki1-Adams-Oshiomole-orisun-saraki-pdp-apc Watch Video
6
Ki Bukola Saraki Tete Fi IPO Re Sile Ni Kiakia O – OSHIOMOLE

orisun

02/08/2018

178

Alaga fun gbogbo egbe APC ni gbogbo orile ede Nigeria; iyen ogbeni Adams Oshiomole ti ke gbajari sita wipe ki Gomina ipinle Kwara teleri ti o je Are fun awon asofin-agba kuro lori oye ti o wa nitori awon idi ti o fi lele ninu iroyin yii. Ni ibi Ipade ti Oshimo

Watch Video
babangida-baba-elections-2019 babangida-baba-elections-2019 Watch Video
5
E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019

orisun

18/07/2018

172

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019 Ogagun teleri ti o ti dari orile ede Nigeria tele-tele ti f’owo si gbigbe igba ibo fun eni kan laarin awon egbe oselu ti o wa ni orile ede Nigeria; awon eniyan ko gbaagbo sugbon o wipe eni t

Watch Video
Fayemi-reno-omokri-ekiti-apc-government-gospel-tv-host Fayemi-reno-omokri-ekiti-apc-government-gospel-tv-host Watch Video
2
E Wo Nnkan Ti Reno Omokri Woye Pe Yoo Sele Labe Ijoba Fayemi Ni Ipinle Ekiti

orisun

18/07/2018

124

Alabarin ati alabapin Aare lati egbe PDP (Peoples Democratic Party) iyen ogbeni Reno Omokri ti woye nnkan ti yoo sele labe ijoba Fayemi ni ipinle Ekiti. Omokri ti o je alabarin fun Aare tele ri; Goodluck Ebele Jonathan so oko oro merin lori nnkan buruku ti o w

Watch Video

No more postsLoading posts ...Load More

No more postsLoading posts ...Load More