Alabarin ati alabapin Aare lati egbe PDP (Peoples Democratic Party) iyen ogbeni Reno Omokri ti woye nnkan ti yoo sele labe ijoba Fayemi ni ipinle Ekiti.

Omokri ti o je alabarin fun Aare tele ri; Goodluck Ebele Jonathan so oko oro merin lori nnkan buruku ti o woye wipe yoo sele labe ijoba Fayemi.

Lakoko, o wipe:

– Bi Ipinle Ekiti se ri bayii, yoo baje si

– O wipe; Fayemi ko ni mu ise re ni okunkundun

– Fayemi yoo gbe gbogbo ebi sori Fayose lati fi boju

– Ni igba ti awon eniyan ipinle Ekiti ba pariwo lori wahala ti Fayemi yoo mu wa; yoo da won lohun pelu nnkan ti Fayose fi sile.

Ogbeni Omokri yii so lori ero alatagba Twitter re leyin ti enikan beere lowo re nipa ohun ti Ayodele Fayose gbe ori-oye se ni igba ti o fi wa ni ijoba.

Fayemi-reno-omokri-ekiti-apc-government-gospel-tv-host

 

Add comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ATumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.