Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

image
Description

Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

Adari Ere ati ogbountarigi elere so wipe Oko Mercy Aigbe n tahun si oun lori ero ayelujara wipe ki oun fi Mercy sile.

Iyalenu ni o je fun wa bi Lege miami se so wipe oun ko ni nnkankan pelu Osere tiata naa.

E wo fidio ti o wa loke yii ki e gbo iroyin naa ati iroyin miran ∏↑

E TUN LE KA EYI: Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni