YORUBA CHANNEL

ORIGINAL CONTENT

WATCH US ON YOUTUBE

ORISUN LOGO-3

WITH

ORISUN LOGO-3

ORISUN IS THE SOURCE OF ALL YORUBA CONTENT

WATCH OUR PROGRAMMES BELOW

From Miliki Express to Ojumo Ire and Other programmes

Orisun is a CONTENT HOUSE

CLICK HERE

Featured Videos

Browse Videos By Category

MILIKI EXPRESS

All Videos : 56 Videos posted

image Watch Video
3
NJE O Dara Ki A Maa Ni Emi IDariji Ninu Igbeyawo?

orisun

19/12/2017

44

NJE O Dara Ki A Maa Ni Emi IDariji Ninu Igbeyawo? Olatorera ati akegbe re Tope ni o n jiroro lori pataki Idariji laarin loko-laya ati nnkan ti o maa n fa Aini idariji. Gege bi a ti mo wipe, IFE ni akoja ofin, lai si ife, ko le si idariji-ese. Beeni o pon danda

Watch Video
image Watch Video
2
Idi Ti EMI IDARIJI Ko Wopo Laarin Ololufe Meji

orisun

13/12/2017

44

Idi Ti EMI IDARIJI Ko Wopo Laarin Ololufe Meji Lori Eto Miliki Express, Olatorera ati akegbe re Tope ni o n jiroro lori pataki Idariji laarin loko-laya ati nnkan ti o maa n fa Aini idariji. KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON E wo fidio yii ki

Watch Video
image Watch Video
1
KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON

orisun

12/12/2017

60

KINI IDI TI E RO WIPE AWON OKO SE MAA N NA IYAWO WON Lara Olubo Pelu awon alejo re soro nipa Ife laarin loko at i laya bi won ti se n gbe papo. Eyi ti o ka oju wa ninu awon nnkan ti won so ni nina Iyawo ti awon okunrin miran maa

Watch Video
image Watch Video
2
Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko

orisun

12/12/2017

75

Bi Obinrin Se Le Gbe Igbeaye Irorun Lodede Oko Lara Olubo ni Olootu eto wa loni, Won si fi asiko naa ba alejo won soro lori IGBEAYE OBINRIN LODEDE OKO. Nje Kini Eyin Naa Ro Nipa Bi Obinrin se n gbe Ile Oko. E wo fidio ti o wa loke yii ki e le ri Watch Video

image Watch Video
4
Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O

orisun

12/12/2017

31

Lege Miami Pariwo Sita Wipe Oun Ko Ni Nnkan Se Pelu Mercy Aigbe O Adari Ere ati ogbountarigi elere so wipe Oko Mercy Aigbe n tahun si oun lori ero ayelujara wipe ki oun fi Mercy sile. Iyalenu ni o je fun wa bi Lege miami se so wipe oun ko ni nnkankan pelu Oser

Watch Video
image Watch Video
3
Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni

orisun

11/12/2017

42

Bi Yetunde Obanla Se Yi Pada Lati Musulumi Si Kristieni Yetunde ObaNla pelu LARA OLUBO joko lori eto toni lati so isipaya ti o faa ti awon se yipada lati inu esin Musulumi si ti Kiriyo gege bi baba Yetunde Obanla se maa n pee. Omo Alhaji bi awon miran ti maa n

Watch Video
image Watch Video
3
AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON

orisun

05/10/2017

67

AWON FANS MI NI IMISI GBOGBO ORIN MI – JAYWON OLORIN JAYWON ti aye mo ko awon orin bii This Year, Facebook Love, Joromi Jomi, Banuso ati beebeelo ni alejo wa lori Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo… O dahun ibeere ti o nii se pelu bi o se n ri im

Watch Video
image Watch Video
4
AWON ANFAANI TI MO TI JE NI IDI ISE THEATRE- YOMI FABIYI

orisun

05/10/2017

51

Yomi Fabiyi je osere ere theatre ti o odu ti o kin se aimo fun oloko, iyen tunmo si wipe ilumooka ni osere yomi Fabiyi…. Ogbeni Yomi Fabiyi tun je osere ti o tun mu adari ere mo gbogbo awon nkan ti o n se, Awon ere ti Yomi Fabiyi ti se ni Metomi, Ife

Watch Video

BO SE N LO

All Videos : 33 Videos posted

image Watch Video
2
Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

orisun

21/03/2018

64

Eku dede asiko yii eyin ololufe Orisun. Lori eto #Bosenlo t’oni ni a ti soro nipa ibasepo okunrin ati obirin ninu ile paapajulo eni ti o ye ki o se olori ile. Lara nnkan ti enikan so ni wipe O dara ki okunrin je olori nitori wipe lati inu itan wa ni a ti

Watch Video
image Watch Video
1
Christian Ati Aisan Ogbe Inu (ULCER) Lori Bosenlo HEALTH

orisun

12/12/2017

57

Christian Ati Aisan Ogbe Inu Lori Bosenlo Gegebii Kristieni, Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se si Watch Video

image Watch Video
1
AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII

orisun

12/12/2017

48

AISAN OGBE INU ATI NNKAN TI A LE SE SII Nje O Dara Ki A Maa Gba awe ti a ba je eni ti o ni aisan Ogbe inu? Alejo wa ti o je oni’mo ero Ilera soro nipa awon nnkan ti o maa n fa Ogbe Inu ati awon nnkan ti a le se Watch Video

Alex-Iwobi-and-Kelechi-Iheanacho-orisun Alex-Iwobi-and-Kelechi-Iheanacho-orisun Watch Video
3
NIGERIA GBODO NA ZAMBIA TABI GBA DRAW NI WORLD CUP QUALIFIER

orisun

03/10/2017

78

Super Eagles ti ilu Nigeria ma gba boolu idije ese keta (3rd round) world cup qualifier pelu egbe agbaboolu Chipolopolo ti ilu zambia ni papa isere (stadium) Uyo ni October 7th, 2017 ni dede ago marun. Awon atokun wa lori eto Bosenlo Sports ri si oro idije boo

Watch Video
foods-good-for-stomach-ulcer-orisun foods-good-for-stomach-ulcer-orisun Watch Video
1
IRU OUNJE TO DA FUN ENI T’ONI STOMACH ULCER

orisun

03/10/2017

62

Stomach Ulcer je arun ti o ma je yo ni inu ikun omo eniyan ti a ko ba se awon nkan ti o ye ki a se. Ni opo igba ni awon ti o ba ni Stomach Ulcer o kin mo iru ounje ti o ye ki won ma je, Opo igbe ni won ma Watch Video

image Watch Video
4
GBOGBO NKAN TI O YE KI E MO NIPA ARUN MEASLES

orisun

26/09/2017

47

MEASLES je arun ti o kan omode ati agbalagba, measles je arun ti o ma n fa iku ti a ko ba tete fun ni itoju ti o ye, Kini awon nkan ti o ye ki e mo nipa arun measles yii ati wipe ki lo n pe ni arun measles… e wo fidio ….. Watch Video

image Watch Video
2
BI A SE LE SE ITOJU OMO TO BA NI MEASLES

orisun

25/09/2017

97

MEASLES je okan lara awon arun buruku ti o ma n se okunfa opolopo iku omode ati agbalagba ni orile ede Nigeria. Awon ti o ma n kan agbake Arun Measles yi ma n ko lati ofurufuru (air) latari iko (cough) ati sinsin (sneeze) lati odo awon ti o ti ni tele. Ti eeya

Watch Video
image Watch Video
3
“Iku Awon Obi Mi, O je Ki n ka iwe siwaju”-Okiki Afolayan

orisun

20/09/2017

58

Movie Director to pe oju osuwon ni Ogbeni Okiki Afolayan je I won ba n soro nipa didari ere agbelewo ni eka Yoruba nollywood ni Nigeria. Ogbeni Okiki Afolayan je alejo wa lori eto Bosenlo pelu atokun wa Bimbo Ojuoge, won si soro niap iro eeyan ti Okiki Afolaya

Watch Video

AKIIYIN O

All Videos : 17 Videos posted

image Watch Video
2
AWON ILUMOOKA TI O MAA N FI OWO OLA GBA AWON Ti O N BO LONA LOJU

orisun

12/12/2017

48

AWON ILUMOOKA TI O MAA N FI OWO OLA GBA AWON Ti O N BO LONA LOJU Civilized Omobadan pelu akegbe re, MC ABBEY joko lati soro lori bi won ti n fowo ola gbaAwon olorin, awon osere ti won n fi orin olorin, ere elere ati awon ti o n se ohun atinuda ti Watch Video

image Watch Video
3
Angeli Yo Si Mi Loju Ala Pe Kin Bere Ise Iranse- Atorise

orisun

28/09/2017

36

Olorin Atorise ni alejo wa lori A KI YIN O pelu Mc abbey ati Civilized Omo Ibadan; Ni ori episode yii Atorise so nipa bi oun se bere ise iranse; ati bi oun se di iranse olorun,bi oun se di eni to ni ile ijosin ori oke…. E YUN LE KA: Idi Ti Won Fi N

Watch Video
image Watch Video
2
Orin Emi Gbodo Wa Lati Oke- Olorin Psalm100

orisun

19/09/2017

47

Gospel Music ni Psalm100 nko… Olorin emi, Psalm100 ni alejo wa lori eto A ki yin o pelu Mc abbey ati Civilized Omo Ibadan, won si soro nipa orin emi ti gbogbo aiye mo won fun. Won ba wa soro lori nkan ti won n pe ni orin emi ati bi a se le da Watch Video

image Watch Video
3
Awon Social Networking Sites Toi Won Nlo Ju Ni Agbaye

orisun

08/09/2017

25

Social Networking Sites ti po no ita nisiyin pelu bi lilo ero social media ti wa wopo laarin ati omode ati agbalagba. laipe yi ni iwe awon social networking sites ti awon eeyan n lo ju jade ti a si ni wipe ki a mu wa fun yin ni ori eto A ki yin o Watch Video

image Watch Video
2
Eni To Ba Ma Se Theatre Gbodo Ni Ife si-Osere Kola Olaiya

orisun

25/08/2017

32

Kola Olaiya je okan ninu awon agbaagba osere theatre ti won ti pe ni idi sise ere agbelewo, ti odu won o kin se aimo fun oloko. Awon sinima ti won ti se ko lonka

Watch Video
image Watch Video
3
Ipe Ni Orin Emi Je Si Mi, Kii Se Ise – Evang Ajao Sabach

orisun

25/08/2017

68

Gospel Musician, Lady Evangelist Ajao Adedumola Sabach ni alejo wa lori eto A ki yin o ti ojo isinmi pelu atokun eto wa Sogorenikeji Abiona.

Watch Video
image Watch Video
2
Nkan Ti A Le Se Ti A Ba Gbagbe Password

orisun

10/08/2017

53

Password si awon iyara social media wa bi Facebook, Twitter, Google, Instagram, Youtube ati beebe lo, a ma n gbagbe won nigba mi ti o si ma n mu wa pa iyara

Watch Video
image Watch Video
4
Dropbox, Dictionary Ati Awon Apps To Dara Fun Akeko

orisun

10/08/2017

24

Social Media ni nkan ti o gbode laye isin ti o si n mu aye dero fun ati omode ati agbalagba, pelu idasile Facebook, Twitter, Google, Instagram, Youtube ati beebe lo.

Watch Video

AWON ORIN AMULUDUN

All Videos : 2 Videos posted

Gbayi-kiss-daniel-cdq-music Gbayi-kiss-daniel-cdq-music Watch Video
4
CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI

TeeMirror

27/03/2018

100

CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI Asiwaju agba fun Ileese NSNS ti awo orin ogbeni CDQ ti n jade ni o parapo pelu Kiss Daniel ti o sese di oga ara re naa lati gbe orin ‘Gbayi’ jade fun igbadun awon ololufe won. Gbogbo wa

Watch Video
image Watch Video
4
MAYORKUN (@iammayorkun) FT. DAVIDO – BOBO

TeeMirror

27/03/2018

94

MAYORKUN FT. DAVIDO – BOBO Leyin ti omo Toyin Adewale ti Aye mo si Mayorkun ti fi awon orin aladun dawalola; awon orin bii “Sade“, “Mama” and “Che Che“ ni o darapo mo oga re Davido lati gbe orin akoko ni odun 2018 kale ti o si pee ni “

Watch Video

ISEMB'AYE

All Videos : 6 Videos posted

image Watch Video
3
Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Ona kakanfo Je Ni Ilu Oyo

orisun

31/05/2018

50

Leekan Sii, E WO Bi A Se N FI Are Onakakanfo Je Ni Ilu Oyo Ileese Telifisan Orisun wa nibi ayeye Ifijoye ti won se ni Ilu Oyo fun Are Onakakanfo tuntun ni awujo awon omo Yoruba ni Ilu Nigeria ati kaakakiri gbogbo agbaye ti awon omo Nigeria wa. Pelu Ijo ati ayo

Watch Video
isese-day-osun-osogbo-orisun isese-day-osun-osogbo-orisun Watch Video
4
Aregbesola Pe August 21 Ni Isese Day

orisun

18/08/2017

48

Ijoba Ipinle Osun ti pe ojo aje, august 21, 2017 ni public holiday lati se ajoyo Ojo Isese ti won ma n se ni odoodun. Isese day je ojo ti won ma n gba isinmi fun awon elesin isembaye

Watch Video
image Watch Video
3
Orun Ni Gbogbo Eegun Ti Wa, Oosa si ni won

orisun

11/08/2017

48

Nibo ni eegun ti wa? Ta lo da won si aye? Ni bo ni won ti jeyo? Kini Ipinlese awon eegun? Opo awon asa kan kan ti sonu sugbon sise odun eegun

Watch Video
image Watch Video
3
Bi Won Se Se Ayeye Odun Eegun Ni Ilu Ode Remo

orisun

11/08/2017

70

egun je okan gboogi lara awon asa ati ise  ile yoruba. Ni aipe yi ni won se ayeye odun eegun ni ilu ode remo ti atokun eto isembaye lo mu wa fun eyin ololufe re....

Watch Video
image Watch Video
1
#Isembaye: Eegun Ile Ati Idi Ti A Fi N Bo Eegun

orisun

10/08/2017

71

Yoruba je eya ti o kun fun orisirisi ise ati asa ti o to won sona ninu gbogbo nkan ti won n se lati aye ba aye ti won si n fi le omo lowo lati ori generation kan si ekeji.

Watch Video
ISEMBAYE ISEMBAYE Watch Video
1
Odun Ijesu Ni Ilu Ogidi Lori Eto Isembaye

orisun

04/01/2017

50

Odun Ijesu je odun ti a ma n se ni odoodun lati fi inu didun han pe Isu titun jade. Orisun je Telifisan ti o n ko omo ni ede ati asa pelu ise.

Watch Video