Sorry, there are no posts found on this page. Feel free to contact website administrator regarding this issue.
Category - OJU OJA
ATumo Gbogbo Oro
LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII
E BAWA SORO LORI INSTAGRAM
- 1 month ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV _ @orisuntv ki yin pe e be odun kan loni. _ Igba odun, odun kan ni lagbara eedua. _ HAPPY BIRTHDAY TO YOU @yemialade #birthday #celebrant #orisuntv #media
- 1 month ago by orisuntv #AyeyeLoriOrisun #OrisunTV _ Oloye JAGUN BABAFEMI BRANCH ( @jagun_femibranch ) Inu wa dun; A si n baa yin yo fun oye ti e gba gege bii JAGUN ASA ti ilu EDE, ti ipinle OSUN. _ L'AGBARA EEDUA, OYE A MORI O.(Ase) _ #events #celebrity #royalty #orisuntv #nollywood
- 1 month ago by orisuntv #IroyinLoriOrisun #OrisunTV _ IDI TI OPO ENIYAN FI N DARAPO MO EGBE OSELU SDP _ Minisita teleri, Ojogbon TUNDE ADENIRAN so wipe egbe oselu SDP (Social Democratic Party) ti setan lati gba awon eniyan ti o fe fi egbe oselu won tele Sile lati darapo mo won. _ Adeniran tesiwaju lati s'alaye pe egbe naa ti di ohun ti gbogbo awon ti o feran "Ijoba awa ara wa" ti a mo si DEMOCRACY to feran lati darapo no. _ Fun ekunrere iroyin e lo si ori ero ayelujara wa ni WWW.ORISUN.TV
- 1 month ago by orisuntv #MCM #OrisunTV _ Gbajumo Okunrin ti Ojo Aje Oni ni ( @iamkissdaniel ) _ TANI O LE SO ORUKO ABISO (REAL NAMES) KISS DANIEL _ E fi eesi yin sinu aye ifesi (Comment Box) _ #puzzle #celebrity #musician #orisuntv #mcm
- 1 month ago by orisuntv #AyeyeLoriOrisun #OrisunTV _ A ki gbogbo abiyamo aye pe e ku odun oni. _ Edumare a je ki e jere ise owo yin _ HAPPY MOTHER'S DAY TO ALL THE MOTHERS IN THE WORLD. _ #mothersday #events #orisuntv #womanhood
- 2 months ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV - A ba yin dupe fun Olohun to je ki ojo toni se oju yin. A gba ladura pe emi yin a gun ninu owo ati alafia. - Eku ojo ibi oni o. - @bintaayomogaji #OrisunTV #birthday #celebrity #nollystar #nollywood
- 2 months ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV _ Inu wa dun gidi gaan ni wipe Oba oke kayin ye lati se Ojo ibi miran lori ile alaaye. _ Lagbara Eedua...Iwaju Iwaju ni e o maa lo o. HBD @ProfOsinbajo _ #birthday #politician #celebrity #orisuntv
- 2 months ago by orisuntv #AyeyeLoriOrisun #OrisunTV _ A ki gbogbo obinrin fun ti ayeye INTERNATIONAL WOMENS DAY #iwd2018 toni. _ Akanda ni Obinrin je, Ayanfe Olohun si niwon pelu, nitoripe awon ni irinse Eledua fun bibisi ati iresi omo eda Adamo. _ Fun idi eyi, itesiwaju won ati aduro ti won, se gbodo je wa logun. _ #pressforprogress #iwd2018 #metoo #womenempowerment #genderequality #orisuntv
- 2 months ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV _ A ba yin yo pe e le odun kan loni. _ Olohun a je ki e se opo odun laye. @tawaajisefinni _ #birthday #nollywood #actor #orisuntv #movies
- 2 months ago by orisuntv THIS IS OUR OFFICIAL YOUTUBE PAGE PLEASE ... DISREGARD ANY OTHER CHANNEL faking the ORISUN TV Channel.... We don’t Show movies on our YOUTUBE PAGE !!!!!!
- 2 months ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV _ A ba yin yo loni fun ojo ibi ti omo yin. Edumare a ba yin da la gba, yio gbe aye se oun rere. _ @iamnino_b #nollywood #celebrity #birthday #fatherslove #orisuntv
- 2 months ago by orisuntv
- 2 months ago by orisuntv #OsereLoriOrisun #OrisunTV _ Nje aso olopa ye gbajumo osere @odunomoadekola ?? KINI Ẹ O KỌKỌ ṢE TI Ẹ BA PADE RẸ LOJU POPO? _ #celebrity #actor #nollywood #movies #orisuntv
- 2 months ago by orisuntv #OsereLoriOrisun #OrisunTV _ Ta lo le so fun wa bi iya wa, agba osere Idowu Phillips se bere si ni lo oruko MAMA RAINBOW gege bi oruko itage won? _ Fun eni ti o ba mo, e fi esi sinu aye isoro (Comment Box) _ #quizzers #celebrity #nollywood #veteran #orisuntv
- 2 months ago by orisuntv #OsereLoriOrisun #OrisunTV _ Ewo tun leleyi bayi. Bi a se ri eleyi , a ni ka se afihan re, ki eyin na bawa rerin _ Bawo bi isinmi yin sen lo? _ #weekend #orisuntv #actor #funnyposts #nollywood
- 2 months ago by orisuntv #OsereLoriOrisun #OrisunTV _ Gege bi e ti mo pe oni ni ojo Jimoh ti awon oloyinbo pe ni FRIDAY. Opo eeyan, lo ma feran ati wo aso ibile loni. _ Eyi ni imura wa lori orisun fun toni _ @mydemartins
- 2 months ago by orisuntv #OjoIbiLoriOrisun #LoriOrisun _ Igba Odun, Odun kan ni, a ba yin yo pe e le odun kan loni. Emi a se pupo e. _ @sunkanmi_omobolanle #birthday #celebrant #actor #orisuntv #nollywood
- 2 months ago by orisuntv OjoIbiLoriOrisun #OrisunTV _ A ki yin, a si ba yin yo pe e le kun ni ojo toni. Odun yi a san yin sowo, omo, alaafia ati aiku baale oro. _ Eku Ojo Ibi Oni _ @gabbylucciii
- 2 months ago by orisuntv #IroyinLoriOrisun #OrisunTV _ Aya aare oriledey wa, AISHA BUHARI dupe lowo Olohun fun ipadabo omo re @buhari_y lati ilu oba ni ibi ti o ti lo gba itoju fun ijamba keke to sele si bi Osu meji _ Fun ekunrere iroyin e lo si ori ero ayelujara wa ni WWW.ORISUN.TV