Category - MILIKI EXPRESS

Anfani Kiko Makeup Lodo ASOJULOGE yato si Youtube

Make Up sise yala fun ara eni tabi fun elomiran ti wopo ni ayika wa bayii. Opo obirin ni o ti ko bi won se n se makeup yala fun lilo araeni tabi gegebi ise owo. Ti won ba si bi won, won a ni awon ko ni owo asojuloge kan tabi ni ori ero youtube… Lori eto, a n bi alejo wa ti o je...

Igbese Akoko Ti O Ye Ka Gbe Fun Eto Ayeye IGBEYAWO

Marriage (igbeyawo) je oun idunnu ati ayo ti gbogbo obi gba ni adura fun omo ati oun ti omo gan paapaa gba fun ara re. Won ni ti omode ba ti too loko, oye ko loko ni…. Nje ti omode ba ti se tan lati ni oko Igbeyawo, kini igbese akoko ti o ye ki o gbe (oko ati Iyawo) ati wipe kini...

Ipa Ti Osere Obirin N Ko Ninu Ere Lo N Fa Iwokuwo Won- Olajuwon Adewunmi

Ipa Ti Osere Obirin N Ko Ninu Ere Lo N Fa Iwokuwo Won- Olajuwon Adewunmi

Ni enu ojo meta yii, opo eniyan lo n soro nipa iwokuwo awon osere obirin wa ninu awon sinima agbelewo wa, ti awon osere gan ni oro kan tabi meji so lori oro naa. Osere Olajuwon Adewunmi ti o ti se opo ere agbelewo je alejo lori miliki express pelu bimbo ati ayinke won si so oro lori akori...

Ijoba Orun Ko Fee, Mi O Le Ya TATTOO – Oyita

Osere Oyita ni alejo wa lori Miliki Express Pelu Ayinke ati Bimbo ti won si soro nipa imnua ati iwokuwo awon osere obirin ni nollywood, storyline awon ere agbelewo nollywood ati idi ti awon story won fi ma n jo ara won. Lori eto, Ayinke bi Osere Oyita boya o le ya tatoo tabi lu eti, ahan...

Mo Ti N Fi Ise Aderinposhonu Pa Owo Lati Ile Iwe- KOFFI

Koffi je aderinposhonu agba ni orile ede nigeria. Ko wopo ninu awon aderinposhonu ki o si gbajumo di asiko yii. Ogbeni Koffi je alejo wa lori eto Miliki Express pelu Ayinke ati Bimbo won si ba wa soro nipa igba ti awon bere ise adeirinposhonu  ati bi won se dagba se kekere…   E...

Ona Orisirisi Ti A Le Fi Style Natural Hair

Oge sise ti ko ja ki a kan maa ko attachment sori tabi ki a ma pack irun wa si oju kan na ni ojoojumo. Oge ti o ti n wopo laarin awon odo obirin ati awon agbalagba gan ni Natural Hair. Awon ologe obirin isinyi ma n feran ki won maa gbe irun natural won, eyi si ni a n gbe yewo lori eto...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.