Category - BO SE NLO

Gbogbo Nkan Ti O Ye Ki E Mo Nipa Iba LASAA

Lassa Fever je aisan ti o ti n fe ma wopo ni awujo ni isinyi. Iwadi fi ye wa wipe eni ti o ba ti ni aarun lassa o ki ni symptom kan kan bee ti o ami kankan ba je yo yoo je bi fever, weakness, headaches, vomiting, ati muscle pains. Kini Lassa Fever? Ki Ni awon Ami Re?….   E TUN...

ONA ORISIRISI TI A N GBA PADANU OMI NI AGO ARA WA

Omi(Body Fluid) je ara awon nnkan ti o je ki ara maa je ara. Ti ko ba si Eje ati omi ni ara omo eniyan, a ko le so wipe Eniyan ni wa. Loni lori Eto wa Bosenlo ni abala Ilera ni Atokun eto wa arabinrin Sekinat Raji ti soro nipa awon ona pataki ti a ko fi oju si ti o maa gbe omi-ara awa...

OHUN TI AISI IDAMORAN LAARIN LOKOLAYA MA N FA NINU IGBEYAWO

IGgbeyawo gba opo suuru ati ife ki o le toro ki osi le fi pe. opo igbeyawo lo ti fi ori shopan laipe ojo nipati pe oko tabi iyawo o ni suuru tabi won o se nkan kan tabi meji ti o ye ki won se la si ko ti o ye. idamoran laarin loko laya se o da? Ibeere yii ni alejo wa ati atokun wa jo...

Idi Ti Nigeria O Se Ni Isokan (Unity)

Nigeria je orile ede ti o kun opo eya eniyan ti o n gbe ni gbogbo rikerike agbegbe re. Nigeria pin si origun merin ti a n pe ni Ila oorun, Iwo oorun, Guusu ati Ariwa.

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.