Category - SHOWS

Bi Won Se N Se Eto Igbeyawo Ni Ile Yoruba

Marriage (igbeyawo) ni ile yoruba,  je nkan pataki; o je nkan iwuri.MArriage (igbeyawo) ti won n se ni aye atijo ti yato si bi won ti n se ni aye isin leyi ti o tii di aye olaju… Bawo ni won se n se ni aye atijo? Kini awon elo ti won lo? E TUN LE KA: Igbese Akoko Ti O Ye Ka Gbe Fun...

OLU JACOBS,SAHEED BALOGUN ATI AWON CELEB TO SE AJOYO NI SEPTEMBER

CELEBRITIES Birthdays tabi ajoyo omiran kankan ti awon celebrities (ilu Mooka) wa ba se ma je nkan ti awa ololufe won maa n fe mo nipa re. Ni osu kesan odun yii (september,2017) awon ilu mooka repete se ajoyo orisirisi, awon eyi naa si la mu wa fun yin lori eto miliki express pelu toyin...

BI AWON OBI SE N SE OKUNFA MOLESTATION

Molestation iyen Fifowokan Eniyan lona aito ni akori eto lori Miliki Express pelu Torera ati Tope. Gbogbo wa lati gbo orisirisi iroyin nipa Fifowokan Eniyan lona aito iyen molestation, amoo ibeere wa ni wipe nje eyin mo awon ona orisirisi ti awon obi n gba se okunfa Fifowokan Eniyan lona...

IDI TI AWON ALASE CITY PEOPLE AWARDS SE PIN AYEYE WON KELEKELE

City People Awards je award ti o ma n fi gbeoriyin fun awon entertainers iba je olorin, osere, movie producers, directors ati awon ti owa ni eyin itage fun ise opolo ti won n se. City People Award ti o wa lati owo awon alase iwe idaraya (magazine) city people ti wa fun bi odun mejo (8yrs)...

“Iku Awon Obi Mi, O je Ki n ka iwe siwaju”-Okiki Afolayan

Movie Director to pe oju osuwon ni Ogbeni Okiki Afolayan je I won ba n soro nipa didari ere agbelewo ni eka Yoruba nollywood ni Nigeria. Ogbeni Okiki Afolayan je alejo wa lori eto Bosenlo pelu atokun wa Bimbo Ojuoge, won si soro niap iro eeyan ti Okiki Afolayan je ati bi won se se kekere...

Orin Emi Gbodo Wa Lati Oke- Olorin Psalm100

Gospel Music ni Psalm100 nko… Olorin emi, Psalm100 ni alejo wa lori eto A ki yin o pelu Mc abbey ati Civilized Omo Ibadan, won si soro nipa orin emi ti gbogbo aiye mo won fun. Won ba wa soro lori nkan ti won n pe ni orin emi ati bi a se le da orin emi mo…. E ba wa kalo…...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.