Category - Entertainment News

omotola-jalade-sola-koso-shadow-parties-orisun

SOLA KOSOKO,SAIDI BALOGUN,OMOTOLA JAJALDE LORI SET ERE SHADOW PARTIES

Omotola jalade ekeinde ti bere ise lori ere agbelewo tuntun ti o pe  i “Shadow Parties” ti awon osere jankan jankan bi Saidi Balogun, Sola Kosoko, Rotimi Salami, Busola Oguntuyo, Jide Kosoko ati Yemi Blaq wa ninu re. Osere Omotola Jalade wan i ori set ere naa bayi ni Ibadan, oyo state...

lizzy-anjorin-orisun

99% Awon Obirin Ni Aje – Lizzy Anjorin

Osere Liz Anjorin tit un bere awon oro isiti re lori ero abanidore instgram re o. Eleyi ti o so da lori awon obirin. Liz Anjorin so wipe Okan di L’ogorun Obirin ni won bi gegebi Aje (witch), ahun (stingy) ati Odaju (heartless) ati wipe ki awon okunrin sa fun obirin emii ti won bat i ni...

Bobrisky-pics-orisun

Mo Ti Gba Olopa Meta Lati So Ile Mi-Bobrisky

Arakunrin ti o feran lati maa mura bi obirin, Bobrisky ti bo si ori ero abanidore instgram page re lati dan enu nipa igba aiye nla ti o n gbe. Arakunrin oun ti yoo ero agbaorosile (comments) kuro lori ero abanidore instagram re, o ko wipe;  “Am not their mate Bobrisky is classy, and...

BUSOLA-oke- ELEYELE-orisun

Mo FI Orin Sile Fun Igba Die Nitori Oko Mi- Busola Oke

Ilumooka Olorin, Busola Oke ti gbogbo wa mo si ELeyele ti kuro ni idi kiko orin fun igba die ti a ko mo idi ti o fi se be nigbati gbogbo aye ti bere sii mo oruko ati awon orin re. Ni ibi iforowanilenu wok an, Busola Oke fi ye won pe idi ti won o fi ri oun nipe oun duro si oke okun tele...

Pa-Ajasco-orisun

“Asiri Ti O Wa Leyin Ori Mi To Pa”- Papa Ajasco

Opolopo eeyan ni o feran ere agbelewo Papa Ajasco and Company ti o n je The Ajasco Family te le sugbon gbogbo eeyan ko lo mo asiri ti o wa leyin ori papa ajasco to paje. Abiodun Ayoyinka ti gbogbo eeyan mo si Papa Ajasco ni o ma n se ere agbelewo ti wale adenuga da sile ni 1996.Ninu...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.