Category - News

Akinwunmi-Ambode-orisun

Ijoba Ipinle Eko Kede No Movement Ni Ale Ni Ikorodu

Ijoba ipinle eko ti kede wipe eto No Movement ranpe maa waye ni agbegbe ikorodu road lati ri daju pe won se ona irinse (pedestrian bridge) omiran  si Fadeyi Bus stop. Ninu atejise ti permanent ssecetary ni Ministry of works, Olujimi Hotonu,fi ounte lu, ijoba eko so wipe….“the main...

KING-SUNNY-ADE-orisun

King Sunny Ade Pe 77yrs Ni Oni, E Ki Won Ku Orire

King Sunny Ade ti o n je Sunday Adeniyi je olorin omo ilu Nigeria, akorin, instrumentalist ati agba ominira fun orin ni Nigeria. Won bi King Sunny Ade ni 22 September 1946 si idile oba ni ipinle Ondo, ti King Sunny Ade si je okan ninu awon Ilu mooka ni idi orin. Lai pe yii, won fi King...

sophie-eniola-orisun

Osere Eniola Badmus Pari Ija Pelu Iya Omo Davido

Osere Eniola Badmus wo iya ija pelu ore re timo timo Sophia momodu ti o je iya omo davido lenu ijometa; sugbon lowo yi ojo wipe Eniola Badmus ti roo daadaa, o siti pinu lati se agba ki o pari ija ti o wa laarin awon mejeeji. E TUN LE KA: Osere Eniola Badmus Na Idaji Million Naira Fun...

omotola-jalade-sola-koso-shadow-parties-orisun

SOLA KOSOKO,SAIDI BALOGUN,OMOTOLA JAJALDE LORI SET ERE SHADOW PARTIES

Omotola jalade ekeinde ti bere ise lori ere agbelewo tuntun ti o pe  i “Shadow Parties” ti awon osere jankan jankan bi Saidi Balogun, Sola Kosoko, Rotimi Salami, Busola Oguntuyo, Jide Kosoko ati Yemi Blaq wa ninu re. Osere Omotola Jalade wan i ori set ere naa bayi ni Ibadan, oyo state...

ANFANI T’O WA NINU YIYAN ISE THEATRE LAAYO

Ise Theatre je ise ti opo obi fi owo si pe ki awon omo lo se latari opo eniyan ti o ti se orire lati ipase ise na bi Baba Adebayo Faleti, Adebayo Salami, Jide Kosoko, Bukky Wright, Mercy Aigbe, Iyabo Ojo, Odunlade Adekola atibeebeelo. Leyin pe o di Ilumooka, awon anfani wo lotun wa ninu...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.