Category - Sport

frank-de-boer-crystal-palace-orisun

Crystal Palace Yoo Coach Frank De Boer Ni Ise

Egbe agbaboolu crystal palace ti yo Adari agbaboolu won Frank De Boer ni ise leyin ojo meta din laadorin ti won fi si ise lati ma dari iko egbe agbaboolu naa. Ni abe adari De boer, Crystal place o ti gbiyanju lati ni ayo kan (1 point) tabi ki won ni goolu eyekan (1 goal) ninu gbogbo games...

Agbaboolu Onazi Ogenyi Se Afihan woran Omo Re

Agbaboolu Onazi Ogenyi Se Afihan woran Omo Re

Agbaboolu Orileede Nigeria, Onazi Ogenyi ti bo si ori ero abanidore Instagram re lati fi she afihan awon aworan to rewa ti omo re obirin ti o se bi lai pe yii. Onazi ati Iyawo re Sandra bi omo obirin ni August 1st si oke okun.   Ni inu oro ti o ko si ori ero abanidore instgram re, onazi...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.