Category - Lifestyle

Ooni-and-Wura-orisun

“Olori Wuraola Le Fe Okunrin Mi Bayi”- OOni Ife

Olori Wuraola ti da Owo Ori Iyawo Re pada. Ooni Ile ife ti kede pe yato si gbogbo nkan ti awn eeyan nso wipe okunrin ti o ba fe iyawo oun teleri ma se alaisi, Iyawo on le fe okunrin ti o ba wun nitoripe oun ti gba owo ori re pada lowo awon ebi re. Hegebi Iroyin ti o te wa lowo lati owo...

el-classico-ronaldo-messi-orisun

Ojo Idije Boolu El Classico Ti Sun Siwaju

Alaga La liga, Javier Tebas ti so wipe El Classico akoko fun season 2017/2018 ti o ma waye laarin real Madrid ati Barcelona ma waye ni 23 december ni ago kan osan (1pm).  Idije boolu yi ye ko waye ni 20th December gegebi ara awon idije titele ki ilu spain to lo fun winter break. Bi o ti...

EDEN-HAZARD-CHELSEA-ORISUN

“Asiko Ti To Fun Chelsea Lati Tun Gba Champions League”-Hazard

Eden Hazard ti gba ife Premier League, League Cup, Europa League, Ligue 1 ati Coupe de France medals ni igba ti o n gba boolu fun egbe agbaboolu Lille sugbon gbogbo ife ti o ti gba yi o to ti UEFA Champions League ti o fe gba pelu egbe agbaboolu Chelsea. Igba ti egbe agbaboolu Chelsea...

frank-de-boer-crystal-palace-orisun

Crystal Palace Yoo Coach Frank De Boer Ni Ise

Egbe agbaboolu crystal palace ti yo Adari agbaboolu won Frank De Boer ni ise leyin ojo meta din laadorin ti won fi si ise lati ma dari iko egbe agbaboolu naa. Ni abe adari De boer, Crystal place o ti gbiyanju lati ni ayo kan (1 point) tabi ki won ni goolu eyekan (1 goal) ninu gbogbo games...

Dammy-Krane-orisun

Ipe lati odo olorun ni atimole mi je”- Dammy Krane

Owo sokun olopa te Olorin Dammy Krane ti won ti mo le ni Miami ni 2nd of June fun jiji credit card ati identity fraud ni ilu Miami. Won fi esun mesan adigunjale kan ni  in Miami-Dade criminal court fun credit card forgery ati grand theft sugbon won ti gbe ejo na kuro ni court. Krane ti so...

eniola-badmus-orisun

Osere Eniola Badmus Na Idaji Million Naira Fun Aseje Ojo Ibi Re

Osere Nollywood, eniola Badmus ti jade lati se alaye oye ojo ori e.  Osere naa ti o se ojo ibi re ni ana ti awon ololufe ati ebi e fi atejise ojo ibi ranse si se alaye nipa oro na.   “Yes, today is my birthday, and I am so happy and fulfilled about it. I give God the glory. I am 34 today...

E Tumo Gbogbo Oro

LARA AWON FIDIO WA TO DANGAJIA JU LOSE YII

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.