Category - Hot news

BIMBO-THOMAS-SON-JAYDEN-ORISUN

Osere Bimbo Thomas Fi Aworan Omo Re Yangan

Osere Bimbo Thomas ti a mo si Bursty ninu ere jenifa fi opolopo aworan omo re jayden han lori ero abanidore instagram. Omo Bimbo thomas, jayden pe omo odun kan ni aipe yi ti won si se ni alarinrin

Enyeama Ma Pada Si Super Eagles- Gernot Rohr

Oludari egbe agbaboolu super eagles of nigeria, gernot Rohr ti so wipe goalkeeper super eagles teleri Vincent Enyeama ma pada si iko agbaboolu super eagles ti ara ra ba ti dangajiya.

BabyMama Sepe Fun Osere Mustapha Sholagbade

Osere Mustapha Sholagbade se se igbeyawo alarinrin pelu afesona re ti o n gbe ni ilu USA lai pe yi ti ore ati ojulumo pejo lati ba yo sugbon ko je iroyin ayo fun afesona ti o n fe tele.

E Tumo Gbogbo Oro

Ipolowo

BOURNVITA
BOURNVITA @50

Gbajumo Wa

FUNKE AKINDELE-BELLO
Akindele Olufunke Ayotunde (popularly known as Funke Akindele, born August 24, 1976 in Ikorodu, Lagos State, Nigeria) is a Nigerian actress. She came to limelight after featuring in popular United Nations Population Fund (UNFPA) sponsored sitcom; I Need to Know, which ran from 1998 to 2002.

Awon Eto Wa Lori Akiiyin Losu Yii

E Bawa Soro Lori Twitter

E BAWA SORO LORI INSTAGRAM

Subscribe to Blog via Email

Enter your email address to subscribe to this blog and receive notifications of new posts by email.